Ìdíje Madrid, Juventus: Àwọn àwòràn mánigbàgbè
Oríṣun àwòrán, Getty Images
Mario Mandzukic ló kọ́kọ́ gbá góòlù wọlé ní iṣẹ́jú kejì
Oríṣun àwòrán, Getty Images
Mario Mandzukic tún jẹ góòlù míràn ní ìṣẹ́jú kẹtàdínlógójì
Oríṣun àwòrán, Getty Images
Oríṣun àwòrán, Getty Images
Isco góòlù ṣùgbọ́n alamójútó ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ naa wọ́gilé e
Oríṣun àwòrán, Getty Images
Àṣìṣe aṣọ́lé e Real Madrid, Navas fún Juventus láǹfàní láti gbá bọ́ọ̀lù kẹta wọ àwọn rẹ̀
Oríṣun àwòrán, Getty Images
Matuidi gbá góòlù kẹta sínú àwọ̀n Real Madrid lati sọ àpapọ̀ góòlù ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ wọn di mẹ́ta-mẹ́ta, 3-3.
Oríṣun àwòrán, Getty Images
Alamójútó ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ naa Oliver lati ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì pè fún gbé e siílẹ̀ ko gba sílé lẹ́yìn tí Benatia (Juventus) ti Vazquez (Real Madrid) lójú ilé
Oríṣun àwòrán, Getty Images
Alamójútó ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ naa Oliver lati ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì lé aṣọ́lé Juventus, Gianluigi Buffon fun sísọ̀rọ̀ òdì sí alamójútó ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ naa
Oríṣun àwòrán, Getty Images
Ronaldo gbá bọ́ọ̀lú (penalty) wọlé
Oríṣun àwòrán, Getty Images
Àwọn ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù tí yóò kópa ní ipele to kangun si aṣekagba
Oríṣun àwòrán, Getty Images
Àwọn ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù tí opin de ba irinajo wọn
Oríṣun àwòrán, Getty Images
Ìròyìn tó ṣe kókó
Ìwádìí kíkún lóríi kókó ìròyìn
Ìròyìn tí àwọn ènìyàn fẹ́ràn jùlọ
Content is not available
{{rankTranslation}}