Jọwọ yẹ ẹrọ ayelujara rẹ wo, ki o si tẹ 'show results' lati gbiyanju lẹẹkan si.
Ibo ni orilẹede mi fi si?
Iye ọdun ti ireti wa pe eniyan yoo lo nigba ti a ṣẹsẹ bi, lati orilẹede kọọkan (iye ọdun)
- Ilẹ Afirika
- Ilẹ Asia
- Ilẹ Yuroopu
- N Amẹrika
- Erekusu Oceania
- S Amẹrika
Ọdun mejilelaadọrin nireti wa pe o jẹ ọdun to kere ju ti ẹda yoo lo laye - aadọrin ọdun fun ọkunrin, marundinlọgọrin fun obinrin. Ṣugbọn, eyi n yipada pẹlu ọjọ ori. Fun apẹẹrẹ,ireti wa pe ẹni ti o ti pe ọdun mọkandinlaadọrin yoo lo ọdun mẹtadinlogun si.