Èrò ṣe ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ bi Ilé ṣe takò ìdájọ lori Omo-Agege

Oríṣun àwòrán, Facebook/Nigerian Senate

Àkọlé àwòrán, Iléẹjọ́ ni Ọjọ́ mérìnlá ló yẹ kí Omo-Agege fi jókòó sílé
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 2

Ilé aṣòfin àgbà Nàìjíríà tí lọ ilé ẹjọ kòtẹmílọrùn láti yí ìdájọ Ilé ẹjọ́ gíga ìjọba àpapọ̀ tó dá aṣòfin Omo-Agege padà sílé.

Kété ti adájọ Nnamdi Dimgba tí ilé ẹjọ gíga apapọ ni Abuja wọgi le àṣẹ lọ gbélé rẹ ti ilé aṣòfin pa fún Omo-Agege ni Ilé ti kọ iwe ẹjọ láti takò ìdájọ náà.

Bákan náà ní won fi ìkéde ìgbésè yi sójú òpó Twitter ilé aṣòfin agba.

Skip X post
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post

Àríwísí ọtọọtọ ni ìkéde yìí ti mú wà lójú òpó ayelujara pàápàá jùlọ ní Facebook ati Twitter

Oríṣun àwòrán, FACEBOOK/SAMUEL OLAKANLA

Samuel Olakanla gba pe, bi kò ba ni ǹkan miran ninu, kò yẹ ki ilẹ ló sile ẹjọ kotẹmilọrun lori ọrọ naa.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Adesomo Ifedayo ni tirẹ gba Omo-Agege nimọran lati gbọ́ àṣẹ ile-ẹjọ pe

Oríṣun àwòrán, facebook/Adesomoju Ifedayo

Àwọn kàn kúkú bu ẹnu àtẹ lù Omo Agege pé kii ṣe aṣojú dáadáa.

Oríṣun àwòrán, facebook/Prince Joseph Edemenya

Kódà, ọrọ yà lọ bá ìṣúná ọdún 2018, Dino Melaye àti ọgá ọlọ́pàá tí kọ̀ láti yọjú sí ilé aṣòfin.

Oríṣun àwòrán, facebook/olusola ogundeko