Bobrisky rí ẹ̀wọ̀n oṣù mẹ́fà he láìsí ànfàní sísan owó ìtanràn
Oríṣun àwòrán, BOBRISKY/INSTAGRAM
Ile ẹjọ giga ijọba apapọ ti dajọ ẹwọn oṣu mẹfa fun Idris Okuneye ti ọpọ mọ si Bobrisky.
Adajọ Abimbola Awogboro sọ Bobrisky si ẹwọn oṣu mẹfa laisi anfani faini sisan.
Lati ọsẹ to lọ ni adajọ ti paṣẹ pe ki wọn ju Bobrisky si ahamọ titi ti igbẹjọ rẹ yoo fi tẹsiwaju lonii.
Ẹ̀sùn mẹ́fà tó dá lórí ṣíṣe owó náírà lọ́nà àìtọ́ àti àìkéde ohun tí iléeṣẹ́ rẹ̀, BobExpress dá lé lórí ni Bobrisky ń kojú.
Ìròyìn tó ṣe kókó
Ìwádìí kíkún lóríi kókó ìròyìn
Ìròyìn tí àwọn ènìyàn fẹ́ràn jùlọ
Content is not available
{{rankTranslation}}