Wo àwòrán Ọmọọba Harry àti Ìyàwó rẹ̀ nígbà tí wọ́n dé sí Naijiria

Àkọlé àwòrán, Ọmọọba Harry pẹlu Iyawo rẹ lasiko ti wọn ṣe abẹwo si Naijiria
Àkọlé àwòrán, Awọn eeyan n ya fọtọ pẹlu Ọmọọba Harry ati Iyawo rẹ Meghan, ti wọn si n ki wọn kaabọ
Àkọlé àwòrán, Wọn fi ilẹkẹ da Ọmọọba Harry ati Iyawo rẹ Meghan lọla lati bu ọwọ fun wọn gẹgẹ bii eeyan nla
Àkọlé àwòrán, Gomina ipinlẹ Kanduna, Uba Sani ati Ọmọọba Harry nigba to ba lẹ si ipinlẹ Kaduna, ti wọn si tun fi aṣọ agbada nla da lọla.
Àkọlé àwòrán, Awọn onijo ibilẹ fi ijo da Ọmọọba ati iyawo rẹ lara ya lasiko abẹwo.
Àkọlé àwòrán, Gomina Uba Sani ati Ọmọọba Harry ni ile ijọba ipinlẹ Kaduna
Àkọlé àwòrán, Ọmọọba Harry ati Gomina ipinlẹ Kaduna n wo bi awọn onijo ṣe n fi ijo da wọn lara ya ni ile ijọba ipinlẹ Kaduna
Àkọlé àwòrán, Awọn onilu ni ile ijọba
Àkọlé àwòrán, Awọn olorin ibilẹ n fi orin da Ọmọọba lọla.