Queen Elizabeth: Wo àwọn àwòrán tó jẹ́ ojú ní gbèsè nípa ìgbé ayé Ọbabìnrin Elizabeth kejì

Oríṣun àwòrán, Annie Leibovitz

Ọba Elizabeth keji gbe igbe aye to ni aprẹ. A boju wo awọn igbe aye rẹ lori itẹ, lati igba to ti wa ni ọmọ ọwọ titi to fi de ori itẹ eyi to tii pẹ julọ.

Oríṣun àwòrán, PA Media

Àkọlé àwòrán, Elizabeth Alexandra Mary Windsor ni wọn bi ni 21 April 1926,

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Nigba ti ọbabinrin wa ni kekere

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Lati kekere lo ti n huwa bii ẹni to mọ ohun to n se

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Elizabeth ati aburo rẹ, Margaret Rose

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Baba Ọbabinrin Elizabeth jọba

Oríṣun àwòrán, Topical Press Agency / Getty Images

Àkọlé àwòrán, Lasiko ogun abẹle keji, Elizabeth ati aburo rẹ Margaret ni wọn gbe lọ si Windsor. Nibi yii lo ti n ba awọn eeyan orilẹede naa sọrọ lori eto ọmọde kan lori redio BBC

Oríṣun àwòrán, AFP

Àkọlé àwòrán, Ọmọọbabinrin kekere fi ara rẹ jin lati sisẹ lasiko ogun agbaye

Oríṣun àwòrán, Bert Hardy / Getty Images

Àkọlé àwòrán, Lọdun 1940, o fẹ ibatan rẹ kan to jinna pupọ, Philip Mountbatten, ẹni to di Duke ti Edinburgh

Oríṣun àwòrán, PA Media

Àkọlé àwòrán, Ọmọ rẹ akọbi ree, Charles, ti wọn bi lọdun 1948, ko to bi Anne lọdun 1950

Oríṣun àwòrán, PA Media

Àkọlé àwòrán, Ibaṣepọ to dan mọran lo wa laarin oun ati iya rẹ. Awọn mejeji ree nibi ayẹyẹ igbeyawo kan lọdun 1951

Oríṣun àwòrán, PA Media

Àkọlé àwòrán, Losu kinni ọdun 1952, Elizabeth ati Philip rinrinajo lọ soke okun lati soju baba rẹ ti ara rẹ ko ya. Lẹyin ọjọ diẹ, ni ọba waja loju oorun rẹ

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Elizabeth pada sile lọgan. Ẹni ọdun mẹẹdọgbọn ni Ọbabinrin naa nigba to jẹ ọba

Oríṣun àwòrán, PA Media

Àkọlé àwòrán, Ayaba Mary n wo oku Ọba George Karun ti wọn gbe wa si Gbọngan Westminster ni London lati tẹ ni itẹ ẹyẹ. Ọbabinrin Elizabeth duro si ẹyin iya baba rẹ

Oríṣun àwòrán, Universal History Archive

Àkọlé àwòrán, Ninu oṣu Kẹfa ọdun 1953, Elizabeth gba ade ọba ni Westminster Abbey

Oríṣun àwòrán, PA Media

Àkọlé àwòrán, Lẹyin iwuye rẹ, Ọbabinrin Elizabeth keji ati Duke ti Edinburgh yọju si aafin Burkingham nibi ti wọn ti juwọ si awọn araalu

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Awọn eeyan kan juwe iwuye rẹ gẹgẹ bii igab ọtun

Oríṣun àwòrán, PA Media

Àkọlé àwòrán, Ni 1957, Elizabeth ba awọn araalu sọrọ fun igba akọkọ lori ẹrọ amohunmaworan

Oríṣun àwòrán, PA Media

Àkọlé àwòrán, Awọn alaṣẹ ilẹ Gẹẹsi paarọ orukọ awọn idile ori ade lati "Monarchy" si "the Royal Family." Awọn eeyan adugbo n wo Elizabeth lasiko to ṣabẹwo si idile Eddie Hammond, ni Crawley New Town, Sussex lọdun 1958

Oríṣun àwòrán, PA Media

Àkọlé àwòrán, Ọbabinrin Elizabeth maa n lo akoko pẹlu awọn ẹbi rẹ bo tilẹ jẹ pe isẹ kun lọwọ - oun ati ọmọ rẹ, Anne ree ni Windsor Castle

Oríṣun àwòrán, Mirrorpix / Getty Images

Àkọlé àwòrán, Papa iṣere Wembly ni 1966, Elizabeth fun agbabọọlu Bobby Moore ni ami ẹyẹ ife ẹyẹ agbaye lẹyin ti wọn na West Germany ni ami ayo 4-2

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Ni 1966, Elizabeth ṣabẹwo si ilu Welsh ni Aberfan lẹyin iṣẹlẹ ilẹ riri kan nibẹ, eeyan 144 lo ba iṣẹlẹ naa lọ, ti 116 ninu wọn si jẹ ọmọde.

Oríṣun àwòrán, Mirrorpix / Getty Images

Àkọlé àwòrán, Ni 1969 ni wọn gbe fimmu nipa idile Ọbabinrin Elizabeth jade fun igba akọkọ

Oríṣun àwòrán, PA Media

Àkọlé àwòrán, Asiko ti Elizabeth fun ọmọ rẹ Charles ni oye Prince of Wales ree nibi ayẹyẹ kan ni Caernarfon Castle lẹni ọdun mẹsan an.

Oríṣun àwòrán, Lichfield via Getty Images

Àkọlé àwòrán, Elizabetrh ree ni 1972 ninu ọkọ oju omi HMY Britannia lasiko ayẹyẹ igbeyawo rẹ kan

Oríṣun àwòrán, PA Media

Àkọlé àwòrán, Ọbabirnin Elizabeth fẹran aja corgis pupọ

Oríṣun àwòrán, PA Media

Àkọlé àwòrán, Elizabeth lọdun 1977 lasiko to n ṣe ayẹyẹ ọdun marundinlogun lori oye

Oríṣun àwòrán, PA Media

Àkọlé àwòrán, Aarin ọsẹ mẹwaa pere ni Ọbabinrin Elizabeth fi bẹ agbegbbe mẹrindilogoji wo ni UK, o si rin maili 56,000 nibi to ti pade oniruru eeyan kaakiri agbaye

Oríṣun àwòrán, PA Media

Àkọlé àwòrán, Queen Elizabeth II ati Duke ti Edinburgh n juwọ si ọkọ ofurufu Concorde lẹba Barbados

Oríṣun àwòrán, PA Media

Àkọlé àwòrán, Elizabeth ati ọkọ rẹ ni New Zealand lasiko ọdun Polynesia

Oríṣun àwòrán, PA Media

Àkọlé àwòrán, Inu oṣu Kẹjọ, ọdun 1979, ibatan Philip ati Elizabeth Louis Mountbatten ku nipasẹ ibugbamu IRA, wọn si ṣe eto isinku rẹ ni Westminster Abbey

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Ni 1981, akọbi Elizabeth, Charles fẹ Lady Diana Spencer wọn si bi ọmọ meji, William ati Harry, amọ Diana ku ninu ijamba ọkọ kan lọdun1997

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Elizabethy juwe ọdun 1992 gẹgẹ ọdun buburu nitori igbeyawo ọmọ rẹ mẹta tuka, ina tun sọ ni Windsor Castle lọdun naa lọhun

Oríṣun àwòrán, David Cooper/Alamy

Àkọlé àwòrán, Elizabeth yin ibọn SA80 pẹlu awọn ọmọ ẹgbẹ Army Rifle Association ni Bisley

Oríṣun àwòrán, PA Media

Àkọlé àwòrán, Lẹyin iku Diana ni 1997, awọn eeyan bu ẹnu atẹ lu Elizabeth pe kii jade si gbangba mọ, lẹyin naa lo jade sita to si ba wọn araalu sọrọ

Oríṣun àwòrán, PA Media

Àkọlé àwòrán, Ọbabinrin Elizabeth ati arabinrin Susan McCarron jọ mu tii papọ lagbegbe Castlemilk, ni Glasgow

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Lọdun 2000 ni iya Ọbabinrin Elizabeth ṣe ayẹyẹ ọjọ ọgọrun ọdu rẹ loke eepẹ

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Lọdun 2002, ibatan rẹ obinri ati iya ibatan rẹ ọhun jade laye laarin ọṣe meje sira wọn

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Nnkan bii miliọnu kan eeyan lo ba ṣe ayẹyẹ 'golden jubilee' ni ọjọ kẹrin, oṣu Kẹfa

Oríṣun àwòrán, PA Media

Àkọlé àwòrán, ọdun 2005 ni akọbi ọmọ rẹ ọkunrin ṣe igbeyawo fun igab akọkọ

Oríṣun àwòrán, PA Media

Àkọlé àwòrán, Ọbabinrin Elizabeth, Duke ti Edinburgh, ọmọba Wales ati Duchess ti Cornwall nibi ere idaraya kan ni Aberdeenshire

Oríṣun àwòrán, PA Media

Àkọlé àwòrán, Aworan Ọbabinrin Elizabeth ree lasiko to n sa fun ojo nibi ti wọn ti n gba bọọlu Lawn tenis kan ni Roehampton

Oríṣun àwòrán, PA Media

Àkọlé àwòrán, Elizabeth sọrọ nipa ọjọ ogbo lasiko to n sẹ ayẹyẹ ọjọ ibi ọgọ́rin ọdun rẹ

Oríṣun àwòrán, PA Media

Àkọlé àwòrán, Ọkan lara ọjọ ti nu rẹ dun ju ni ọjọ igbeyawo ọmọ-ọmọ rẹ Prince William ati Catherine Middleton ni 2011

Oríṣun àwòrán, PA Media

Àkọlé àwòrán, Atẹgun fẹ gbe fila Elizabeth lọ ni papakọ ofurufu kan lasiko ti noun ati ọkọ rẹ lọ ṣabẹwo si Prince William

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Elizabeth ṣabẹwo si Leicester lọdun 2012
Àkọlé àwòrán, Elizabeth ati Daniel Craig to ṣe fiimu James Bond nibi ayẹyẹ London Olympics

Oríṣun àwòrán, PA Media

Àkọlé àwòrán, Inu Queen Elizabeth dun lasiko ti ẹṣin gbe ipo 207 nibi idije ere sisa kan, oun ati alakoso ẹsin naa, John Warren ree

Oríṣun àwòrán, PA Media

Àkọlé àwòrán, Inu oṣu Kẹsan an, ọdun 2015 ree lẹyin ti Elizabeth ti wa lori oye fun nnkan bii ẹgbẹ mẹrinlelogun ọjọ lori oye, eyii to kọja ti iya-iya rẹ, Queen Victoria

Oríṣun àwòrán, PA Media

Àkọlé àwòrán, Ọbabinrin Elizabeth atawọn ara ile rẹ

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Queen Elizabeth ṣi n ṣiṣẹ titi di ọdun 2018 bo tilẹ jẹ pe agba ti de

Oríṣun àwòrán, Chris Allerton / SussexRoyal

Àkọlé àwòrán, Ẹrin jade lẹnu Elizabeth lasiko to foju ri ọmọ Duke ti Sussex, Archie

Oríṣun àwòrán, PA Media

Àkọlé àwòrán, Queen Elizabeth ree ni Windsor Castle, Berkshire, lẹyin iku ọkọ rẹ, lẹyin ti wọn ti jọ wa papọ fun nnkan bii ọgọta ọdun

Oríṣun àwòrán, Duchess of Cambridge

Àkọlé àwòrán, Ọmọ mẹrin, ọmọ-ọmọ mẹjọ, ati ọmọ-ọmọ-ọmọ mejila lo gbẹyin Queen Elizabeth

All photographs subject to copyright.