Ọdún iléyá 2018: Àwòrán tó jẹ arimaleelọ ni Yidi

Òní ní ọdún Eid il Adha eleyi tí ọpọ èèyàn mọ sí ọdún iléyá.

Àkọlé àwòrán, Jakejado agbàyè ni awọn Musulumi ti kirun lasiko ọdún
Àkọlé àwòrán, Awọn ara Ijebu n se ajọyọ ọdun ileya ni Eid Prayer Arena, Igbeba - Ijebu-Ode
Àkọlé àwòrán, Àwọn ọmọ ọlọdun ń yẹra wo l'Osogbo
Àkọlé àwòrán, Lọjọ ọdún yí àwọn mùsùlùmí yóò ki Irun rakaah méjì leyin tí Imam yoo pa eran tirẹ.
Àkọlé àwòrán, Ọdun Ileya yii dun ni Ijẹbu, ẹsin ni ọmọde yii fi n jaye.
Àkọlé àwòrán, Leyin ti Imam ba pa eran tan ni awon janmọ to ku le pa ti wọn náà
Àkọlé àwòrán, Ní àwọn Aaye ìkìrun ati ọkunrin ati obirin ló peju
Àkọlé àwòrán, Ọdun ba wa ni aye ati ni alaafia, o ye ka jo, ka si tun yọ pẹlu.
Àkọlé àwòrán, Awọn olorin ati oni ilu fi ilu se idaraya fun awọn eniyan lasiko ayeye ileya ti ọdun yii.
Àkọlé àwòrán, Awọn agbagba ni ilu Ibadan naa o gbeyin nibi ọdun ileya ni yidi Agodi, ilu Ibadan.
Àkọlé àwòrán, Ọ̀pọ awọn olutaja lasiko odun yii lo n pariwo ko sowo nita rara lọdun Ileya yii.
Àkọlé àwòrán, Ẹ ri ẹgbẹ wa bi, o yẹ wa n ti wa

Oríṣun àwòrán, @BashirAhmaad

Àkọlé àwòrán, Eegun nla lo n kẹyin igbalẹ́, aarẹ Muhammadu Buhari naa du ẹran ọdun