Nigeria Presidential elections 2023: Wo èsì ìbò ààrẹ fún Tinubu, Atiku, Kwankwaso, Obi

Lọ́dún 1999 ni Naijiria ti bẹrẹ eto iṣejọba alagbada pẹlu ẹgbẹ oṣelu PDP àti ẹgbẹ APC.
Awọn ẹgbẹ mejeeji yii lo ti n ṣakoso Naijiria lati 1999 titi di isinyi ṣugbọn lọtẹ yii awọn ẹgbe\oselu Labour Party naa ti n ba wọn figa gbaga pẹlu NNPP.
Peter Obi ni oludije lati inu ẹgbẹ Labour Party nigba ti Rabiu Kwakwanso jẹ oludije lẹgbẹ NNPP lasiko yii.
Eto idibo Naijiria ọdun 2023: Esi idibo Aarẹ ati ile igbimọ aṣofin
Ọjọ Abamẹta ni awọn ọmọ Naijiria kopa ninu eto idibo gbogbogbo. Oludije mejidinlogun lo n du ipo Aarẹ, bẹẹ lawọn eeyan tun dibo fun awọn aṣofin atawọn aṣojuṣofin. Awọn esi ti ileeṣẹ iroyin BBC n gbe jade jẹ eyii to wa lati ọdọ ajọ eleto idibo INEC.
Esi ibo Aarẹ ọdun 2023
Lati pegede ninu abala akọkọ, oludije gbọdọ ni ibo to pọju ati ida 25% o le ibo ti wọn di ninu ida meji ninu mẹta awọn ipinlẹ to wa ni Naijiria, to fi mọ ilu Abuja
Igba ti a ṣe afikun kẹyin: 19/04/2023, 18:00:25 akoko (GMT+1)
Apapọ esi ibo lakotan
Esi ibo Aarẹ ọdun 2023
Lati pegede ninu abala akọkọ, oludije gbọdọ ni ibo to pọju ati ida 25% o le ibo ti wọn di ninu ida meji ninu mẹta awọn ipinlẹ to wa ni Naijiria, to fi mọ ilu Abuja
Igba ti a ṣe afikun kẹyin: 19/04/2023, 18:00:25 akoko (GMT+1)
Apapọ esi ibo lakotan
Esi ibo Aarẹ lawọn ipinlẹ
Esi ibo Aarẹ lawọn ipinlẹ
Igba ti a ṣe afikun kẹyin: 19/04/2023, 18:00:25 akoko (GMT+1)
Tẹ maapu lati ri esi ibo lẹkunrẹrẹ
Esi ibo ile igbimọ aṣofin lati ẹlẹgbẹjẹgbẹ
Igba ti a ṣe afikun kẹyin: 19/04/2023, 18:00:25 akoko (GMT+1)
| Ẹgbẹ oṣelu | Ijoko |
|---|---|
| All Progressives Congress | 59 |
| Peoples Democratic Party | 36 |
| Labour Party | 8 |
| Awọn ẹgbẹ to ku | 4 |
| New Nigeria Peoples Party | 2 |
Esi ibo ile aṣojuṣofin lati ẹlẹgbẹjẹgbẹ
Igba ti a ṣe afikun kẹyin: 19/04/2023, 18:00:25 akoko (GMT+1)
| Ẹgbẹ oṣelu | Ijoko |
|---|---|
| All Progressives Congress | 159 |
| Peoples Democratic Party | 104 |
| Labour Party | 35 |
| New Nigeria Peoples Party | 18 |
| Awọn ẹgbẹ to ku | 9 |
| Idibo ti ko yọri | 35 |
Awọn to ṣagbekalẹ oju opo yii
Designers: Olaniyi Adebimpe and Millicent Wachira; Visual Artists: Mayowa Alabi and George Wafula: Data Journalists: Yusuf Akinpelu and Brian Osweta; Developers; Boaz Ochieng, Marcos Gurgel, Ayu Widyaningsih Idjajaand and David Ayoola; Project Lead: Dorothy Otieno.
Mọ si nipa eto idibo ọdun 2023
Awọn ọdọ Naijriia sọ pe awon ti ṣetan lati dibo lasiko yii pẹlu ariow lori ayelujara.
Ida kan ninu mẹta ninu eeyan to dagba to lati dibo ninu eeyan milionu mtadinlaadọrun to yẹ ko didbo lasiko yii.
Aago mẹjọ aabọ ni eto idibo ti bẹrẹ nibit i awọn eeyan mi ti n sọ pe awọn ko tii ri ibo di ni agbegbe wọn.
BVAS to jẹ Bimodal Voter Accreditation System ni wọn n lo ninu eto idibo ti ọtẹ yii.
Ika owo ati dida oju oludibo mọ ni wọn n lo.
Oludije to ba wọle nilo ibo ida mẹẹdọgbọn ninu ọgọrunun ni o nilo ninu ida meji ninumẹta awọn oludibo ni ipìnlẹ mẹrindinlogoji tó wa ni Naijiria pẹlu Abuja.
Wo bi Esi Idibo naa ṣe n jade nibi yii:,..........

Tani Rabiu Kwankwaso?
Tani Peter Obi ti ẹgbẹ oṣelu Labour?
Tani Atiku Abubakar?
Tani Bola Tinubu ti ẹgbẹ oṣelu APC?


























