Ọlọ́pàá Ondo: Dírẹ́bà ọkọ̀ nìkan ni wọ́n jígbé kìí se àwọn 18
Oríṣun àwòrán, Getty Images
Ile isẹ ọlọpaa ni ipinlẹ Ondo ti ni eto aabo wa ni sẹpẹ fun awọn ara ilu ati awọn arinrinajo ni ipinlẹ naa.
Femi Joseph to jẹ alukoro ni ipinlẹ Ondo lo sọ fun BBC News Yoruba pe awọn eniyan pa ọpọlọpọ irọ nipa ijinigbe naa.
Joseph ni ile isẹ ọlopaa n ṣa gbogbo ipa awọn lati ri i wi pe wọn doola ẹmi dirẹba ti wọn ji gbe lọ.
O fikun wi pe awọn ko mọ nipa owo itọnran ti awọn ajinigbe n beere ni ọwọ awọn ẹbi ẹni ti wọn jigbe, ati wi pe awọn ko fi ọwọ si i.
Laipẹ yii ni iroyin kan gbe e pe awọn ajinigbe naa ti bere fun miliọnu marun un lati fi gba dẹrẹba naa ti wọn jigbe.
Ìròyìn tó ṣe kókó
Ìwádìí kíkún lóríi kókó ìròyìn
Ìròyìn tí àwọn ènìyàn fẹ́ràn jùlọ
Content is not available
{{rankTranslation}}