Abiola Ajimobi: Ẹ wo àwòrán bí ìsìnkú Abiola Ajimobi ṣe lọ!

Akojọpọ aworan isinku gomina ipinlẹ Oyo tẹlẹri, Abiola Ajimobi

Àkọlé àwòrán, Àna olóògbé Abiola Ajimobi, tó tun jẹ́ gómínà ìpínlẹ̀ Kano, Abdullai Ganduje ni bi tó ti n buwọ́lu ìwé àkọlsilẹ̀ níle olóògbé.
Àkọlé àwòrán, Gómínà ìpínlẹ̀ Eko, Babajide Sanwo-Olu sàbẹ̀wò sílé olóògbé
Àkọlé àwòrán, Gomina ipinlẹ Kano ti o tun jẹ ana oloogbe Abiọla Ajimọbi, Abdullahi Umar Ganduje ati gomina ipinlẹ Jigawa, Mohammed Badaru Abubakar ti de si Mọsalaṣi Abiọla Ajimọbi to n bẹ ni Oke Ado niluu Ibadan, nibi ti eto adura ti n lọ lọwọ fun oloogbe

Oríṣun àwòrán, Ajimobi Lives On

Àkọlé àwòrán, Wọn gbe Sẹnetọ Abiola Ajimobi bọ ilẹ ni inu ọgba ile rẹ ni Oluyole, Ibadan.

Oríṣun àwòrán, Ajimobi Lives on

Àkọlé àwòrán, Iroyin ni pe wọn ti sin oku rẹ ni bonkẹlẹ lai jẹ ki awọn oniroyin wọle.
Àkọlé àwòrán, Ita kun fofo awon olopaa naa si wa ni digbi

Oríṣun àwòrán, Ajimobi Lives on

Àkọlé àwòrán, Orin ó digberé gb'ọkàn àwọn èèyàn níbi ìsìnkú Abiola Ajimobi
Àkọlé àwòrán, Ko ju eeyan ogun pere ti wọn jẹ ko wa ni ibi isinku naa, ni ṣe lawọn eniyan duro sita.

Oríṣun àwòrán, Ajimobi Lives on

Àkọlé àwòrán, Ni nkan bii ago mẹwaa kọja iṣẹju marun owurọ yii ni wọn sin in.

Oríṣun àwòrán, Ajimobi Lives on

Àkọlé àwòrán, Deede ago mejila ọsan ni wọn yoo ṣe adura idagbere fun un ni Mọṣaaṣi. Sen. Ishaq Abiola Ajimobi to wa ni Oke Ado, Ibadan.
Àkọlé àwòrán, Bayii ni gbogbo igboro ti kun nibi isinku gomina Abiola Ajimobi

Oríṣun àwòrán, Ajimobi Lives on

Àkọlé àwòrán, Wọ́n ti sin Abiola Ajimobi! Ó di gberééé

Oríṣun àwòrán, Ajimobi Lives on

Àkọlé àwòrán, Deede ago mejila ọsan ni wọn yoo ṣe adura idagbere fun un ni Mọṣaaṣi. Sen. Ishaq Abiola Ajimobi to wa ni Oke Ado, Ibadan.