TANPAN Conference: Àwọn ilúmọ̀ọ́káá kalẹ̀ sí Ibadan

Oríṣun àwòrán, Realyomifabiyi

Àkọlé àwòrán, Mo le gbe ọ, O ju bayi lọ ni Yomi Fabiyi s fun Mide Martins

Oríṣun àwòrán, odunomoadekola

Àkọlé àwòrán, Ọdunlade Adekọla ati Fausat Balogun ni wọn dijọ maa n kopa iya ati ọmọ ninu ọpọ ere tiata.

Oríṣun àwòrán, odunomoadekola

Àkọlé àwòrán, A ku ọdun , ẹmi wa yoo se pupọ ọdun laye ni Ogogo ati Ọdunlade n sọ fun ara wọn.

Oríṣun àwòrán, odunomoadekola

Àkọlé àwòrán, Mo tẹ ara mi lọrun pẹlu omi yii, ongbẹ ko dara lara ni Ọdunlade Adekọla n sọ.

Oríṣun àwòrán, odunomoadekola

Àkọlé àwòrán, "Ta lo dagba ju laarin wa, ẹ ba wa da si?" ni Mr Latin n beere.

Oríṣun àwòrán, odunomoadekola

Àkọlé àwòrán, Ọsan to ri gbajumọ ti ko bọ ni awọn mẹẹtẹta yii, odu si ni wọn, wọn kii se aimọ fun oloko lagbo tiata.

Oríṣun àwòrán, odunomoadekola

Àkọlé àwòrán, Ọdunlade Adekọla ni jo ya, ijo ree, jẹ ka jo

Oríṣun àwòrán, Sanyeri02

Àkọlé àwòrán, Sanyeri ni "Ọrẹ jọ mi, mo jọ ọrẹ mi."

Oríṣun àwòrán, Sanyeri02

Àkọlé àwòrán, Awa la wa ri ara wa, bi ologinni ti n ri ọmọ Ẹkun...

Oríṣun àwòrán, Sanyeri02

Àkọlé àwòrán, Ọdunlade Adekọla ni melo ni gbogbo ara Sanyẹri, ti oun ko lee gbe soke.

Oríṣun àwòrán, Antarthywill

Àkọlé àwòrán, Awa agba aja, ti kii ba awo jẹ naa peju sibi ipade Tanpan

Oríṣun àwòrán, Iteledicon01

Àkọlé àwòrán, Ọrẹ law n se, a ko ja rara ni awọn agba osere yii sọ

Oríṣun àwòrán, Realyomifabiyi

Àkọlé àwòrán, Gbogbo wa la peju

Oríṣun àwòrán, odunomoadekola

Àkọlé àwòrán, Ẹrin keke lẹnu awọn osere tiata meji, Ọdunlade Adekọla ati Bọlaji Amusan, ta mọ si Mr Latin.