Ayàwòrán: ọpọlọ, sùúrù àti agbára ni mò ń lò fún iṣẹ́ mi
Ìgbàkigbà ni ìmísí má a ń wá sí ọkàn mi fún yíya àwòrán
Olọ́tọ̀ ní tòun ọ̀tọ̀, Olumide Orẹṣegun tó ń ya àwòrán ní, kété tí mo ba ti ní ìmísí fún iṣẹ́ àwórán kan, ni màá kọọ silẹ̀ tàbí ki ń tẹ̀ẹ́ si orí fóònù mi.
Maa pe àwọn ọmọ jọ foríkorí wá ǹkan ti mò n fẹ́ lò, ki ó tó di odindin.
O mẹnuba oriṣii àwòrán to wà, ti wọn kọ́ nile ìwé pé:
- Àwọn kan Àṣamọ̀ - Abstract
- Àwọn kan Afòyemọ̀ - Realism
- Àwọn kan maa n duro lọ́kàn ẹni - Impressionism
- Àwọn kan maa ń ṣafihan - Expressionism
- Àwọn kan n sọ nipa ọjọ́ ọ̀la - futuristim
- Àwọn kan pegedé nínú afòyemọ̀ - Hyper- realism
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
Olumide bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú eyi tó n wa lati ókàn rẹ̀ ni yíyà kí ó tó di ọ̀gá àgbà lẹ́nu iṣẹ́ rẹ̀.
O ni òun fi làákàyè ṣagbekalẹ àwón ohun eelo irinṣẹ aworan yiya to wọn ni Naijiria.
Ìròyìn tó ṣe kókó
Ìwádìí kíkún lóríi kókó ìròyìn
Ìròyìn tí àwọn ènìyàn fẹ́ràn jùlọ
Content is not available
{{rankTranslation}}