Arsenal tẹ̀síwájú nínú idije Europa
Oríṣun àwòrán, ALEXANDER NEMENOV/AFP/Getty
Ẹgbẹ agbaboolu Arsenal ti pegede lati tẹsiwaju nínú ìdíje Europa league pẹlu apapọ àmì ayo mẹfa si mẹta ti CSKA Moscow.
Ọmi ayo meji ni awọn ati CSKA jijọ gba ni Moscow.
Ni abala akọkọ ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ naa, ọrọ fẹ ṣebi a'n gba ona mi yo nígbà tí CSKA Moscow ṣáájú je ayo méjì.
Sugbọn àwọn ìkọ Arsene Wenger da ayo méjì padà.
Danny Welbeck lo kọkọ gba góòlù akọkọ wọlé ní abala keji ifẹ̀sẹ̀wònse náà .
Oríṣun àwòrán, Getty Images
Aaron Ramsey palemo ètò ni iṣẹju igbeyin ifẹ̀sẹ̀wònse náà.
Ni bayi Arsenal yóò kojú ọkan nínú Athletico Madrid, Marseille tàbí Salzburg ti awọn náà tẹsiwaju sí abala to kangun sí asekagba idije Europa.
Ìròyìn tó ṣe kókó
Ìwádìí kíkún lóríi kókó ìròyìn
Ìròyìn tí àwọn ènìyàn fẹ́ràn jùlọ
Content is not available
{{rankTranslation}}