BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Àwọn abala
Ìròyìn
Eré ìdárayá
Fídíò
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Ìròyìn
Eré ìdárayá
Fídíò
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Wo àwòrán Ọmọọba Harry àti Ìyàwó rẹ̀ nígbà tí wọ́n dé sí Naijiria
Àkọlé àwòrán,
Ọmọọba Harry pẹlu Iyawo rẹ lasiko ti wọn ṣe abẹwo si Naijiria
11 Èbibi 2024
Àkọlé àwòrán,
Awọn eeyan n ya fọtọ pẹlu Ọmọọba Harry ati Iyawo rẹ Meghan, ti wọn si n ki wọn kaabọ
Àkọlé àwòrán,
Wọn fi ilẹkẹ da Ọmọọba Harry ati Iyawo rẹ Meghan lọla lati bu ọwọ fun wọn gẹgẹ bii eeyan nla
Àkọlé àwòrán,
Gomina ipinlẹ Kanduna, Uba Sani ati Ọmọọba Harry nigba to ba lẹ si ipinlẹ Kaduna, ti wọn si tun fi aṣọ agbada nla da lọla.
Àkọlé àwòrán,
Awọn onijo ibilẹ fi ijo da Ọmọọba ati iyawo rẹ lara ya lasiko abẹwo.
Àkọlé àwòrán,
Gomina Uba Sani ati Ọmọọba Harry ni ile ijọba ipinlẹ Kaduna
Àkọlé àwòrán,
Ọmọọba Harry ati Gomina ipinlẹ Kaduna n wo bi awọn onijo ṣe n fi ijo da wọn lara ya ni ile ijọba ipinlẹ Kaduna
Àkọlé àwòrán,
Awọn onilu ni ile ijọba
Àkọlé àwòrán,
Awọn olorin ibilẹ n fi orin da Ọmọọba lọla.
Móríwú
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
01:13
Fídíò,
Mọ̀ nípa àwọn ewu méje tó rọ̀ mọ́ ṣíṣe ìdí ńlá, BBL, àti ìlànà tí wọ́n ń gbà ṣe é
, Duration 1,13
01:03
Fídíò,
Àwọn ọ̀dọ̀ ilẹ̀ Africa ni ìlera ọpọlọ wọn pé jù lọ láàgbáyé-Ìwádìí
, Duration 1,03
01:57
Fídíò,
DJ Cuppy ṣàlàyé ìdí tí inú rẹ̀ fi dùn pé Ààrẹ Tinubu ṣàbẹ̀wò sí ilẹ̀ UK
, Duration 1,57
04:18
Fídíò,
Ìlú kan rèé lábẹ́ ìjọba Ogun àmọ́ ilẹ̀ Benin ni wọn ti ń bímọ, pọn omi, ta ọjà pẹ̀lú ìnira ńlá
, Duration 4,18
04:54
Fídíò,
Agboolé Akọni: Ohun tó fa ìjà láàárín Afonja àti Aláàfin Aole àti bí Alimi ṣe dìtẹ̀gbàjọba lọ́wọ́ Afonja nítorí ẹ̀sìn
, Duration 4,54
01:27
Fídíò,
Ohun tó máa ń mú kí ọkùnrin máa rí àpẹrẹ pé òun lóyún nígbà tí ìyàwó rẹ̀ bá lóyún; COUVAD sydrome ni, ohun tó sì ń fàá rèé
, Duration 1,27
04:16
Fídíò,
Torí pé àwọn èèyàn ò rí ààrín èmi àti Allwell Ademola ni wọ́n fi ń sọ pé a ń fẹ́ra, àmọ́ Ọlọ́run yan án sínú ayé mi láti tọ́ mi sọ́nà – Rotimi Salami oṣere
, Duration 4,16
00:59
Fídíò,
Àwọn awakọ̀ ti bẹ̀rẹ̀ sí ní tò ra epo pẹ̀lú bí owó epo ṣe ń lọ sókè
, Duration 0,59
03:03
Fídíò,
Wo tọkọtaya tó ń gba àwẹ̀ Lent àti Ramadan papọ̀
, Duration 3,03
01:44
Fídíò,
Wo àkóbá tó wà nínú àgbàdo, ẹ̀wà àti ata tí a lọ̀ ní ẹ̀rọ ìlọta fún ẹ̀dọ̀ àti kíndìnrín rẹ
, Duration 1,44
05:52
Fídíò,
Ohun táwọn oníṣẹ̀ṣe sọ fún àjọ INEC lórí ìdìbò àti pàtàkì ọdún Ọ̀ṣun Osogbo tí wọ́n fi yí ọjọ́ ìdìbò gómìnà padà
, Duration 5,52
Ìròyìn tó ṣe kókó
"Mo ra ‘Sim Card’ táwọn ajínigbé ti fi gbá owó ìtúsílẹ̀ N50m, pa ẹni tí wọn jí gbé, mo bá dèrò àtìmọ́lé"
wákàtí 3 sẹ́yìn
Kí ló fà á tí Funke Akindele kò fi dáhùn kíkí tí Toyin Abraham kí i lóde?
wákàtí 3 sẹ́yìn
Agbèbọ́n tún ṣọṣẹ́ ní Plateau, pa ọ̀pọ̀ èèyàn lọ́jọ́ Ìsinmi Ọ̀pẹ
wákàtí 4 sẹ́yìn
Ìwádìí kíkún lóríi kókó ìròyìn
Mo ti bí ọmọ márùn-ún tẹ́lẹ̀ kí n tó bí ibẹ́rin báyìí, ìbejì ni scan sọ fún mi- Ìyá Ìbẹ́rin
23 Ẹrẹ̀nà 2026
Mo tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ẹ̀yin ọmọ Naijiria fún iná ọba tí kò sí lásìkò yìí- Adelabu
25 Ẹrẹ̀nà 2026
Èmi ṣì ni alága NURTW- MC Oluomo
25 Ẹrẹ̀nà 2026
Ohun tó máa ṣẹlẹ̀ sí ẹni tí kò bá dìbò fún Tinubu lọ́dún 2027 rè é - Portable
25 Ẹrẹ̀nà 2026
'Biola Bayo, mo fà ẹ́ sí kóòtù Ọlọ́run'-Princess bú sígbe torí Baba Ijesa tí Biola Bayo gbé wá sóri ètò
25 Ẹrẹ̀nà 2026
NBA,Ẹgbẹ́ Amòfin Naijiria bínú sí Sowore tó pàtẹ ìpàdé akọ̀ròyìn nínú kóòtù
25 Ẹrẹ̀nà 2026
Àwọn jàndùkú ya wọ ọ́fíìsì Amotekun l'Osun, jí ìbọn wọn gbé sálọ
25 Ẹrẹ̀nà 2026
Àwọn agbésùnmọ̀mí tó jí ọmọ ìjọ ECWA mẹ́jọ gbé ní Kwara ń bèèrè bílíọ̀nù kan náírà fún ìtúsílẹ̀ wọn
25 Ẹrẹ̀nà 2026
Àlàyé lórí ọ̀nà tuntun tí Amẹrika fẹ́ gbà láti fìyà jẹ orílẹ́èdè Iran
26 Ẹrẹ̀nà 2026
Ìròyìn tí àwọn ènìyàn fẹ́ràn jùlọ
1
Kí ló fà á tí Funke Akindele kò fi dáhùn kíkí tí Toyin Abraham kí i lóde?
2
Agbèbọ́n tún ṣọṣẹ́ ní Plateau, pa ọ̀pọ̀ èèyàn lọ́jọ́ Ìsinmi Ọ̀pẹ
3
Àjọ̀dún Lisabi 2026 gbọ̀rẹ̀gẹ̀jigẹ̀ lóòótọ́, àmọ́, a ṣẹ̀ṣẹ̀ ń mẹ́yẹ bọ̀ lápò ni - Amosun
4
Wo ohun tó mú àyájọ́ ọjọ́ ìsinmi 'Palm Sunday' yàtọ̀
5
Agbébọn tó kó òṣìṣẹ́ mẹ́ta lọ nílé ìwòsàn l'Ondo, ohun tí a mọ̀ rèé
6
Agbébọn 38 pàdé ikú lọ́wọ́ ológun Naijiria, wọ́n gba ìbọn AK-47 àti àdó olóró lọ́wọ́ wọn
7
Ìdí tí mi ò ṣe kí ń lo ọkọ mi ṣùgbọ́n tí mo máa ń lo ọmọ mi nínú fídíò àwàdà tí mò ń ṣe rèé - Kiekie
8
Rògbòdìyàn PDP: Wo àwọn tọ kọ̀yìn sí ìpàdé àpapọ̀ igun Wike tí yóò wáyé l'Abuja lónìí
9
Lẹ́yìn ìpàdé àpapọ̀ l'Abuja, wo àwọn tí yóó tukọ̀ APC fọ́dún mẹ́rin
10
Afẹ́fẹ́ òjò fa ìjàmbá ọkọ̀ ńlá l'Osogbo