New Year's Day 2023: Àwọn àwòrán tó làmìlaaka rèé nípa bíí àwọn ènìyàn ṣe ṣe ayẹyẹ ọdún tuntun 2023

Àkọlé fídíò, Ẹ wo bi awọn ara Australia ṣe ajọyọ ọdun tuntun pẹlu ina alaranbara ni Sydney harbour.
    • Author, Jasmine Andersson
    • Role, BBC News

Kaakiri agbaye ni awọn eniyan ti ṣe ayẹyẹ ibẹrẹ ọdun tuntun 2023.

Awọn ara orilẹede Kiribati ni agbegbe Pacific nation of Kiribati ni wọn kọkọ ri ọdun tuntun, ki orilẹede New Zealand to tẹlẹ lẹyin wakati kan.

Ẹgbẹgbẹrun awọn eniyan lo korajọ si ilu Sydney ni orilẹede Australia lati wo bi wọn ṣe fi ina fireworks ṣere.

Àwọn àwòrán tó làmìlaaka rèé nípa bíí àwọn ènìyàn ṣe ṣe ayẹyẹ ọdún tuntun 2023 kaakiri agbaye.

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Orisiri ohun alaranbara ni wọn ju si oke ni Time Square lorilẹede Amẹrika wẹrẹ ti aago mejila lu, ti wọn si bọ si inu ọdun tuntun 2023.

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Awọn oluworan fo fun aayọ bi aago mejila sẹ lu ni Times Square, ni Amẹrika.

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Nise ni awọn ololufẹ yii fi ẹnu ko ara wọn ni ẹnu wẹrẹ ni aago mejila lu ni ibẹrẹ ọdun 2023 ni agbegbe Cologne, Germany

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Bi wọn ṣe ṣe ayẹyẹ ọdun tuntun ni yii ni agbegbe Heroes' Square ni Budapest, Hungary.

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Ayẹyẹ ọdun tuntun ree ni Colombo, Sri Lanka

Oríṣun àwòrán, Reuters

Àkọlé àwòrán, Ni ẹgbẹ omi agbegbe Rio de Janeiro, Brazil ni awọn eniyan ti ṣe ayẹyẹ ọdun tuntun 2023

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Bi oorun akọkọ ṣe yọ ree ni ilu Seoul, ni orilẹede South Korea ni ọdun 2023

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Pipo carri

Oríṣun àwòrán, Reuters

Àkọlé àwòrán, Awọn eniyan gbe balloon dani ni agbegbe Wuhan, lorilẹede China

Oríṣun àwòrán, PA Media

Àkọlé àwòrán, Ni ṣe ni ina banga n dun lakọ lakọ ni ilu London, ni Ilẹ Gẹẹsi

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Bi ayẹyẹ ọhun ṣe lọ ni agbegbe Nile ni ilu Cairo, Egypt

Oríṣun àwòrán, EPA

Àkọlé àwòrán, Bi ayẹyẹ ọdun tuntun ṣe lọ ni agbegbe Madrid ree

Oríṣun àwòrán, Reuters

Àkọlé àwòrán, Bi ayẹyẹ ọdun tuntun ṣe lọ ni Arc de Triomphe ni Paris ree

Oríṣun àwòrán, Reuters

Àkọlé àwòrán, Ina alaranbara gba gbogbo agbegbe Bangkok Chao Phraya River ninu ọdun tuntun.

Oríṣun àwòrán, BIANCA DE MARCHI/EPA-EFE/REX/Shutterstock

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Abẹ igi ni awọn miran ti wo ayẹyẹ ọdun tuntun ni agbegbe Sydney Botanic Gardens ni Australia

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Lati ojumọ ni awọn eniyan ti pejọ lati mu aye ti wọn yoo duro si ni alẹ lati wo ayeye, Sydney Opera House

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Agbegbe Hagley Park, ni Christchurch, lorilẹede New Zealand ree ni ọjọ ọdun

Oríṣun àwòrán, Reuters

Àkọlé àwòrán, Awọn eniyan ko ara jọ ni ilu Seoul, South Korea

Oríṣun àwòrán, Reuters

Àkọlé àwòrán, Ilu Tokyo, ni orilẹede Japan ko gbẹyin nibẹ.

Oríṣun àwòrán, Reuters

Àkọlé àwòrán, Orin ati ariya ni orisiriri ni ilu Tokyo

Oríṣun àwòrán, Reuters

Àkọlé àwòrán, Ina alaranbara ni awọn eniyan tan ni agbegbe Hong Kong

Pipo celebrate new year for Taipei, for T

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Orilẹede Taiwan naa ko gbẹyin nibẹ.

Oríṣun àwòrán, Reuters

Àkọlé àwòrán, Bangkok, Thailand

Oríṣun àwòrán, Getty Images