BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Ojude Ọba 2019: Àwọn èèkàn lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti péjú fún ayẹyẹ ojúde Ọba
Àkọlé àwòrán,
Ojude Oba tí ọdún yìí ti gbéra sọ pẹ̀lú oníruuru àwọn aṣọ alárànbara yorùba to ń wúni lóri, Awọn ẹgbẹ́ Tobalàṣẹ obinrin rèé nínú àṣọ okè aláwọ̀ ewé
13 Ògún 2019
'Kò sí ohun tó burú nínú bí Ajimobi ṣe dá Yewande tó pa ọkọ rẹ̀ sílẹ̀'
Àwọn Fadá mẹ́rin gbà itusílẹ̀ lọwọ àwọn ajínigbé
Samuel Okwaraji: Ó pé ọgbọ̀n ọdún tí lónìí ti akọni àgbábọ̀ọ̀lù papo dà
Ẹ ṣe àwárí ọdànran tó bọ mọ́ọ yín lọ́wọ́ - Turkur Buratai
Àkọlé àwòrán,
Gbogbo àwọn ọmọ ẹgbẹ́ Gbobaniyi lókùnrin àti lóbìrin ló ti lọ ki ọba aláde lóri ìjòkò
Àkọlé àwòrán,
Lẹ́gbẹ́ lẹ́gbẹ́ ni gbogbo àwọn ti wọ́n péju síbi ayéyé Ojude Oba tí ọdún 2019
Àkọlé àwòrán,
Tokùnrin tobinrin ló wọsọ ìgbà níbi àyẹyẹ ojude oba tọdún yìí, Ẹgbẹ́ Bọbakẹ́yẹ Ọkunrin ni àwọn yìí
Àkọlé àwòrán,
Tarúgbó tomidàn ló wà nibi àyẹyẹ yìí, gbogbo oju wọ́n lo gúrégé pèlú, àwọn ẹgbẹ́ bọ́bakẹ́yẹ obinrin rèé
Àkọlé àwòrán,
Gbogbo àwọn olóyè àti èèkàn ìlú ló péjú
Àkọlé àwòrán,
Kìí ṣe àwọn ẹgbẹ́ gbẹ́ jọdá nìkàn ló péju, àwọn ọdọ náà jáde wá láti yẹ́ àṣ]a ìbílẹ̀ sí
Àkọlé àwòrán,
Aláàfin Ọyọ, ikú bábá yèyé, Ọba Lamidi Adeyemi náà péjú síbi ayẹyẹ ojúde Oba ní'lú Ijebu
Àkọlé àwòrán,
Gómínà ìpínlẹ̀ Ogun, Dapo Abiodun àti Awùjalẹ̀ Ijẹ̀bú Ọba Sikiru Adetona
Àkọlé àwòrán,
Gómìnà tẹ́lẹ̀rí ní ìpínlẹ̀ Ogun, Ọtunba Gbẹnga Daniels
Àkọlé àwòrán,
Ẹgbẹ́ Bọ́baguntẹ ilẹ̀ Ijẹbu
Àkọlé àwòrán,
Gbogbo ojú tó ti ríra típẹ tún ni àànfàni láti ṣe "Ẹ k;u àti"
Àkọlé àwòrán,
Ẹgbẹ́ Obafunwaji Obinrin Adedoyin rèé nínú aṣọ ofi aláwọ̀ búlù
Àkọlé àwòrán,
Ẹgbẹ́ Tobalaṣẹ Ọkunrin náà ko gbẹ́yìn
Àkọlé àwòrán,
Gbogbo àwọn ọmọ ẹgbẹ́ Gbobaniyi lókùnrin àti lóbìrin ló ti lọ ki ọba aláde lóri ìjòkò
Móríwú
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
05:19
Fídíò,
Timini ṣàlàyé fún BBC lórí ohun tó ṣẹlẹ̀ láàrin òun àti Funke Akindele
, Duration 5,19
04:19
Fídíò,
Bàbá àti ọmọ ni Olubadan àti Makinde, kò yẹ kí ìjà máa wáyé láàárín wọn - Balogun Olubadan
, Duration 4,19
03:37
Fídíò,
N kò ní darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ ADC àmọ́ bí APC bá fún mi ní ipò míì, màá gbà á - Iyabo Obasanjo
, Duration 3,37
02:44
Fídíò,
Ilẹ̀ Cameroun fi tijó-tìlù pàdé Pope Leo XIV
, Duration 2,44
02:33
Fídíò,
Ẹni tó bá ní kò sí ayé, ayé wà o, ohun tó jẹ mọ́ ọ̀rọ̀ ẹ̀mí wà nínú iṣẹ́ tíátà - Tosin Olaniyan
, Duration 2,33
01:25
Fídíò,
Kí ló sọ àwọn ológbò di gbajúmọ̀ orí ayélujára ní Instabul?
, Duration 1,25
03:16
Fídíò,
Kí ni ẹ̀ṣẹ̀ wa ní Ido-Ani, tí ìjọba Ondo fi pa wá tì láìsí ilé ìwòsàn àti ojú ọ̀nà tó dára? – Aráàlú fárígá
, Duration 3,16
04:12
Fídíò,
Àwọn òṣèré òde òní nílò láti máa ṣàgbéyẹ̀wò ìtàn tí wọ́n ń kọ, a kìí ṣe eégún oníhòhò - Lere Paimo
, Duration 4,12
06:34
Fídíò,
Ọba Ido-Osun pàṣe kí wọ́n ti ilé ìjọsìn tí pásítọ̀ rẹ̀ lọ gbàdúrà lójúbọ Osun Osogbo pa
, Duration 6,34
05:05
Fídíò,
Kí ni ohun abàmì tó wà nínú Omi Oko ní Ilesa, tí wọn ṣe kọ́lé fún-un, yọ fèrèsé àti ìlẹ̀kùn sí?
, Duration 5,05
04:00
Fídíò,
Ìwé mẹ́fà ni mo kà, kí ń tó kọ́ iṣẹ́ Rédíóníìkì, ipasẹ̀ ẹgbọ́n mi kan níbẹ̀ ni mo gbà dé ìdí iṣẹ́ tíátà - Okele
, Duration 4,00
04:32
Fídíò,
"Mo ra ‘Sim Card’ táwọn ajínigbé ti fi gbá owó ìtúsílẹ̀ N50m, pa ẹni tí wọn jí gbé, mo bá dèrò àtìmọ́lé"
, Duration 4,32
Ìròyìn tó ṣe kókó
Wíwẹ̀ ní àárọ̀ tàbí alẹ́: Èwo ló dára jùlọ?
ìṣẹ́jú 54 sẹ́yìn
Amẹ́ríkà àti Iran ní ìjíròrò ń so èso rere àmọ́ kò tíì sí ìfẹnukò
wákàtí kan sẹ́yìn
Wo ohun tí wàhálà àṣejù yóò ṣe sí àwọ̀ ara à rẹ nígbà tó bá rẹ̀ ọ́
wákàtí 3 sẹ́yìn
Ìwádìí kíkún lóríi kókó ìròyìn
'Òkú mẹ́rìndínlọ́gọ́ta ni mo kà láàárín ìlú, ọ̀pọ̀ ló fọ́nká sínú igbó'
14 Ìgbé 2026
Amẹ́ríkà gbégi dínà Strait of Hormuz láti dí Iran lọ́wọ́ gbígbé epo gba ibẹ̀, China figbe ta pé ewu ń bẹ̀, bí owó epo ṣe wọ́n sí ní àgbáyé
14 Ìgbé 2026
Àwọn ọmọ Iran kọminú lórí bóyá ogun Amẹ́ríkà lè tẹ̀síwájú tàbí bẹ́ẹ̀ kọ́ lẹ́yìn tí ìpàdé àláfíà forí ṣánpọ́n
14 Ìgbé 2026
Lẹ́yìn ìwọ́de tako ìjínigbé, Aiyedatiwa ṣàbẹ̀wò sáwọn agbègbè tí ààbò ti mẹ́hẹ, ó ní ajínigbé 100 tó ń ṣọṣẹ́ l‘Ondo ní ọwọ́ ti bà
15 Ìgbé 2026
Dárúkọ pẹ̀lú ẹ̀rí tó dájú àwọn tó fi rìbá lọ̀ ọ́ láti gbé ìgbésẹ̀ ìyọnípọ̀ Makinde bíbẹ́ẹ̀kọ́... - Olórí ilé aṣòfin àná
15 Ìgbé 2026
Kí ni alága àjọ INEC ṣe tí MURIC ṣe yarí pé lílọ ni yóò lọ àmọ́ táwọn ọ̀dọ́ ìlú rẹ̀ ṣèwọ́de àtìlẹ́yìn fún un?
15 Ìgbé 2026
Àbọ̀ ìwádìí BBC lórí ikú ìyàwó Wòlíì olùdásílẹ̀ ìjọ tó ń ṣe ọ̀pọ̀ èèyàn ní kàyééfì
15 Ìgbé 2026
Àlàyé rèé lórí ìdí tí ààrẹ Trump àti Pope Leo XIV ṣe ń tahùn síra wọn
15 Ìgbé 2026
Ìdí rèé tí Iyabo Obasanjo ṣe gba kámú bí gbogbo ẹgbẹ́ APC l‘Ogun ṣe fa Yayi kalẹ̀ bíi olùdíje gómìnà
14 Ìgbé 2026
Ìròyìn tí àwọn ènìyàn fẹ́ràn jùlọ
1
Agbẹ̀bí méjì kó sí gbaga ọlọ́pàá l'Ondo lẹ́yìn ikú ìyá àtì ọmọ tuntun jòjòló méjì
2
Ṣé ó yẹ kí àwọn obìnrin máa fi ẹ̀yìn sùn tí wọ́n bá fẹ́ bímọ?
3
Amẹ́ríkà àti Iran ní ìjíròrò ń so èso rere àmọ́ kò tíì sí ìfẹnukò
4
Ademola Adeleke pe ilé ìfowópamọ́ UBA àtàwọn alága kánsù APC lẹ́jọ́
5
Wo ohun tí wàhálà àṣejù yóò ṣe sí àwọ̀ ara à rẹ nígbà tó bá rẹ̀ ọ́
6
Ìjọba Kwara pe Bukola Saraki, Abdulfatah Ahmed àtàwọn mìí lẹ́jọ́ ẹ̀sùn ìpànìyàn
7
Ọba kì í ṣe òṣèlú, Olubadan, ẹ jáwọ́ níbẹ̀ kẹ́ ẹ má baà mú àrífín wá - Balogun Olubadan
8
Àwọn ìdí rèé tí gómìnà kan fi le yọ ọba nípò lábẹ́ òfin
9
Wíwẹ̀ ní àárọ̀ tàbí alẹ́: Èwo ló dára jùlọ?
10
Àlàyé lórí báwọn olùjọ́sìn tó ní ìpèníjà etí ṣé máa ń ṣiṣẹ́ Hajj ní Mecca