BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Coronavirus: Báyìí ni nkan ṣe n lọ ní pápákọ̀ ọkọ̀ òfurufú l'Eko lẹ́yìn tí Coronavirus wọ́lé
Àkọlé àwòrán,
Gbogbo awọn to n wọle, tabi jade kuro ni papakọ ofurufu Murtala Muhammed lo n gba abẹ ayẹwo kọja
29 Èrèlè 2020
Àkọlé àwòrán,
Yatọ si irinṣẹ ti wọn n mu dani, ẹrọ kan tun wa bi kamẹra to n ṣe ayẹwo awọn eero baalu fun apẹẹrẹ aarun Coronavirus
Àkọlé àwòrán,
Oriṣiriṣi awọn oṣiṣẹ eto ilera lo wa ni ikalẹ ni papakọ ofurufu ilu Eko fun ayẹwo awọn arinrinajo
Àkọlé àwòrán,
Koda, wọn gbe omi aporo kokoro aifojuri 'sanitizer' silẹ fun awọn arinrinajo
Àkọlé àwòrán,
Ati oṣiṣẹ ati eero baalu lo n lo iboju lati ba ara wọn sọrọ nitori Coronavirus
Àkọlé àwòrán,
Kii ṣe ita papakọ ofurufu nikan ni ikiyesara ti n waye, gbagbaagba ni kaluku n boju-bomu ninu ọfiisi.
Àkọlé àwòrán,
Ẹrọ ayaworan wa tun gbe oṣiṣẹ eto ilera kan to wa lẹnu iṣẹ t'oun ti iboju ati ìbọ̀wọ́
Àkọlé àwòrán,
Ṣugbọn o, Coronavirus ko da wiwọle ati jijade ni Naijiria duro ni papakọ ofurufu naa. Kẹti-kẹti ni eero n ya lati wọ baalu.
Àkọlé àwòrán,
Igbesẹ oju lalakan fi n sọri ọhun ko yọ awọn oṣiṣẹ ajọ to n risi iwọle-wọde (Immigration) silẹ. Iboju lawọn naa fi ṣe koju o ma ri ibi.
Móríwú
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
02:48
Fídíò,
Awodi: Òrìṣà òjò tí abọrẹ̀ rẹ̀ kò gbọdọ̀ ru ẹrù tàbí ṣe aṣemáṣe pẹ̀lú obìnrin
, Duration 2,48
03:51
Fídíò,
Wọ́n kó Rasheed mérò níbi ìwọ́de EndSARS lọ́dún 2020, ọdún mẹ́fà ló lò lẹ́wọ̀n
, Duration 3,51
02:00
Fídíò,
Àkọsílẹ̀ DNA ṣàwárí àwọn ọmọ tí bàbá wọn ti sọnù fún ọ̀pọ̀ ọdún
, Duration 2,00
05:19
Fídíò,
Timini ṣàlàyé fún BBC lórí ohun tó ṣẹlẹ̀ láàrin òun àti Funke Akindele
, Duration 5,19
04:19
Fídíò,
Bàbá àti ọmọ ni Olubadan àti Makinde, kò yẹ kí ìjà máa wáyé láàárín wọn - Balogun Olubadan
, Duration 4,19
03:37
Fídíò,
N kò ní darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ ADC àmọ́ bí APC bá fún mi ní ipò míì, màá gbà á - Iyabo Obasanjo
, Duration 3,37
02:44
Fídíò,
Ilẹ̀ Cameroun fi tijó-tìlù pàdé Pope Leo XIV
, Duration 2,44
02:33
Fídíò,
Ẹni tó bá ní kò sí ayé, ayé wà o, ohun tó jẹ mọ́ ọ̀rọ̀ ẹ̀mí wà nínú iṣẹ́ tíátà - Tosin Olaniyan
, Duration 2,33
01:25
Fídíò,
Kí ló sọ àwọn ológbò di gbajúmọ̀ orí ayélujára ní Instabul?
, Duration 1,25
03:16
Fídíò,
Kí ni ẹ̀ṣẹ̀ wa ní Ido-Ani, tí ìjọba Ondo fi pa wá tì láìsí ilé ìwòsàn àti ojú ọ̀nà tó dára? – Aráàlú fárígá
, Duration 3,16
04:12
Fídíò,
Àwọn òṣèré òde òní nílò láti máa ṣàgbéyẹ̀wò ìtàn tí wọ́n ń kọ, a kìí ṣe eégún oníhòhò - Lere Paimo
, Duration 4,12
06:34
Fídíò,
Ọba Ido-Osun pàṣe kí wọ́n ti ilé ìjọsìn tí pásítọ̀ rẹ̀ lọ gbàdúrà lójúbọ Osun Osogbo pa
, Duration 6,34
Ìròyìn tó ṣe kókó
Akanmu Epo Akara, bíríkìlà tó gbé orin Àwúrebe ga, tí ọmọ rẹ̀ tún tẹ́wọ́ gbàá
wákàtí 2 sẹ́yìn
Òní ni ìdájọ́ yóò wáyé lórí aáwọ̀ inú ẹgbẹ́ òṣèlú PDP àti ADC
wákàtí kan sẹ́yìn
Àrùn Covid-19 padà bú jáde ní Naijiria, àjọ NCDC àti WHO fi ìkìlọ̀ léde
wákàtí 3 sẹ́yìn
Ìwádìí kíkún lóríi kókó ìròyìn
Àṣírí tú lórí bí ọwọ́ ọlọ́páà ṣe tẹ afurasí 33 tó kọlu ṣọ́ọ̀ṣì CAC Oke Isegun, Eruku ní Kwara
17 Ìgbé 2026
Obìnrin tí wọ́n ṣèèṣì san N100,000 sí àṣùwọ̀n rẹ̀ kọ̀ láti dáwó padà, àwọn èèyàn gbaná jẹ
17 Ìgbé 2026
Ìdẹ̀rùn dé báwọn òṣìṣẹ́ l‘Ogun, wọn yóò gba ìsinmi ọjọ́ kan láàrín ọ̀sẹ̀, ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá owó ọkọ̀ lóṣù
17 Ìgbé 2026
Agbẹ̀bí méjì kó sí gbaga ọlọ́pàá l'Ondo lẹ́yìn ikú ìyá àtì ọmọ tuntun jòjòló méjì
19 Ìgbé 2026
Ṣé ó yẹ kí àwọn obìnrin máa fi ẹ̀yìn sùn tí wọ́n bá fẹ́ bímọ?
19 Ìgbé 2026
Àlàyé lórí báwọn olùjọ́sìn tó ní ìpèníjà etí ṣé máa ń ṣiṣẹ́ Hajj ní Mecca
18 Ìgbé 2026
A gbàgbọ́ pé àlàáfíà yóò jọba ní Cameroon lẹ́yìn àbẹ̀wò Pope Leo XIV- Aráàlú
15 Ìgbé 2026
Kí ni Cute Abiola ṣe, tí omíjé fi ń dà lójú rẹ̀ àmọ́ tí ọ̀pọ̀ èèyàn ń sọ̀rọ̀ si?
16 Ìgbé 2026
Àlàyé rèé lórí ìdí tí ìjọba ṣe yọ ẹ̀sùn fifi owó ṣèrànwọ́ fún ìgbẹ́sùnmọ̀mí kúrò nínú ẹjọ́ ti Malami ń jẹ́
16 Ìgbé 2026
Ìròyìn tí àwọn ènìyàn fẹ́ràn jùlọ
1
Alága ìjọba ìbílẹ̀ Owo tí wọ́n já síhòhò l'Ondo, ohun tí a mọ̀ rèé
2
Àrùn Covid-19 padà bú jáde ní Naijiria, àjọ NCDC àti WHO fi ìkìlọ̀ léde
3
Níṣojú mi báyìí ni wọ́n ṣe ṣá ọkọ mi ládàá pa ṣùgbọ́n mi ò lè pariwo kí wọ́n má bàá ṣá èmi náà-Ìyàwó olóyè Ibadan
4
Wo nǹkan mẹ́tàdínlógún tí ìjọba ti fòfin dè pé wọn ò gbọdọ̀ kò wọlé sí Naijiria mọ́ látòkè òkun
5
Òní ni ìdájọ́ yóò wáyé lórí aáwọ̀ inú ẹgbẹ́ òṣèlú PDP àti ADC
6
Tinubu yọ Mínísítà ètò ìṣúná Wale Edun nípò, fi Taiwo Oyedele rọ́pò rẹ̀
7
Bàbá kan yìnbọn pa ọmọ rẹ̀ méje àti ọmọ ọlọ́mọ kan
8
Peter Okoye kéde àyípadà ọjọ́ ìbí rẹ̀ pẹ̀lú Ìbejì rẹ̀ Paul Okoye, mú ọjọ́ ìbí tuntun fúnra rẹ̀
9
Ìjọba àpapọ̀ wọ àwọn afurasí ọmogun tí wọ́n fẹ̀sùn kàn pé wọ́n fẹ́ dìtẹ̀ gbàjọba Tinubu lọ sílé ẹjọ́
10
Àṣírí tú lórí bí ọwọ́ ọlọ́páà ṣe tẹ afurasí 33 tó kọlu ṣọ́ọ̀ṣì CAC Oke Isegun, Eruku ní Kwara