AfricanDrumFestival: Àwọn àwòrán tó làmìlaaka níbi ayẹyẹ

Awọn aworan to lamilaaka nibi ayẹyẹ ajọ̀dún ìlù nílú Abẹ́òkúta.

Àkọlé àwòrán, Aarẹ Muhammadu Buhari ṣe ileri atilẹyin fun idagbasoke aṣa
Àkọlé àwòrán, Ọna abawọle si ori oke olumọ

Oríṣun àwòrán, AfricanDrumFestival

Àkọlé àwòrán, "Kani a mọ pataki idagbasoke aṣa si idagbasoke eto ọrọ aje wa, a o tẹpa mọ"

Oríṣun àwòrán, AfricanDrumFestival

Àkọlé àwòrán, Ó lé ní ogún ìpínlẹ̀ tí yóò kópa níbi ayẹyẹ àjọ̀dùn ìlù nílẹ̀ Áfíríkà náà

Oríṣun àwòrán, AFRICAN DRUM FESTIVAL

Àkọlé àwòrán, Ijọba ipinlẹ Ogun lo n ṣe agbatẹru ajọdun ilu ilẹ Afirika

Oríṣun àwòrán, AfricanDrumFestival

Àkọlé àwòrán, Awọn ọbalaye kan sara si awọn agbaṣaga

Oríṣun àwòrán, AfricanDrumFestival

Àkọlé àwòrán, Àgba awọn to wa nipo aṣẹ lẹka iṣejọba gbogbo niyanju lati rii wei pe wọn n ṣe koriya fun igbedide aṣa ilẹ Yoruba.

Oríṣun àwòrán, AfricanDrumFestival

Àkọlé àwòrán, Ọkan ojọkan awọn gbajugbaja olosere ni wọn yoo kopa nibi ajọdun naa
Àkọlé àwòrán, Agba osere Nollywood ko gbẹyin nibi ayẹyẹ naa
Àkọlé àwòrán, Awọn onidan naa se bi ọkunrin nibi ayẹyẹ ilu

Awọn aworan yii wa lati ọwọ: BBC ati AfricanDrumFestival