Ìdíje Commonwealth: Nàijíría se ipò kejì ní table tennis
Oríṣun àwòrán, NIGERIA TABLE TENNIS FEDERATION
Ikọ̀ eléré ìdárayá ẹyin oríi tábìlì, Table tennis ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà kùnà àti gba àmì ẹ̀yẹ góòlù níbi ìdíje Commonwealth tó ńlọ lọ́wọ́ ní orílẹ̀-èdè Australia.Àmì ayò mẹ́ta sí òdo ni orílẹ̀èdè India fi gbẹyẹ mọ́ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lọ́wọ́.
Bode Abiodun, Jide omotayo pẹ̀lu Túndé Toríọlá ni wọ́n di ikọ̀ ẹyin oríi tábìlì, Table tenni,s ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà mú nínú ìdíje náà.
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
Nàìjíríà fàgbà han ikọ̀ ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì ní ìpele tó kángun si àṣekágbá pẹ̀lu àmì ayò mẹ́ta sí méjì.
Ìròyìn tó ṣe kókó
Ìwádìí kíkún lóríi kókó ìròyìn
Ìròyìn tí àwọn ènìyàn fẹ́ràn jùlọ
Content is not available
{{rankTranslation}}