You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Bí o ṣe lè dá ìròyìn ẹlẹ́jẹ̀ mọ̀ rèé lórí ẹ̀rọ ayélujára
Awọn ọna ti o le gba ree lati koju iroyin ofege lori ẹrọ ayelujara ati bi o ṣe le daa mọ.
Ni ọpọlọpọ igba, awọn eniyan kii ṣakiyesi lati mọ ibi ti iroyin ti jade wa, lai mọ pe iroyin ofege lo kun ori ẹrọ ayelujara.
Lọpọ igba ni iroyin ofege ti da wahala silẹ, to si ti ṣe akọpa fun ijọba tiwantiwa.
Amọ fidio yii salaye ni ẹkunrẹrẹ bi ẹ ṣe le tete mọ iroyin ẹlẹjẹ ti ẹ ba ri.