You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Àjọ onísirò Nàíjíríà: Àdínkù bá owó ọjà si ìdá mẹ́tàlá
Àjọ onísirò ní Nàíjíríà NBS kéde lọ́jọ́bọ pé àdínkù ti bá owó ọjà lábẹ́lé sí ìdá mẹ́tàlá lósù kẹta ọdún 2018.
Gẹ́gẹ́ bíi àlàyé wọn, ìlànà tí wọ́n fi ń se òdiwọ̀n èlé owó orí ọjà fihàn pé, owó ọjà lọ sókè lósù kẹta ọdún 2018.
Ìkéde tí àjọ náà fisíta sọ pé ìgbà kẹrìnÌdí rèé tí BBC Yorùbá se ń bèèrè pé ǹjẹ́ àwọn aráàlú mọ ipa àdínkù owó ọjà náà lára bí?
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
Ìdí rèé tí BBC Yorùbá se ń bèèrè pé ǹjẹ́ àwọn aráàlú mọ ipa àdínkù owó ọjà náà lára bí?
Nígbà tó ń fìdí ọ̀rọ̀ yìí múlẹ̀, ìyálọ́jà kan, arábìnrin Ọmọlọlá Adéoyè ní lọ́ọ̀tọ́ọ́ ni owó àwọn ọjà ń dínwó díẹ̀díẹ̀ láwọn orí ọjà kọ̀ọ̀kan.
Ẹ gbọ́ arábìnrin Adéoyè síwajú síi: