BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Àwọn abala
Ìròyìn
Eré ìdárayá
Fídíò
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Ìròyìn
Eré ìdárayá
Fídíò
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Ipinlẹ Kwara
Àwọn agbébọn kọlu àwọn to ń gbé òkú lọ itẹ́ ní Kwara, yìnbọn pa fijilanté méjì, jí ọ̀kadà àti ìbọn wọn lọ
28 Ẹrẹ̀nà 2026
0:52
Orin,
Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
, Duration 0,52
27 Ẹrẹ̀nà 2026
Wo bí ìgbẹ́jọ́ àwọn afurasí méje tó dáná sun ilé Asabi Olórìṣà n'Ilọrin ṣe lọ
26 Ẹrẹ̀nà 2026
Àwọn agbésùnmọ̀mí tó jí ọmọ ìjọ ECWA mẹ́jọ gbé ní Kwara ń bèèrè bílíọ̀nù kan náírà fún ìtúsílẹ̀ wọn
25 Ẹrẹ̀nà 2026
À n ṣiṣẹ́ kárakára láti dáàbò bò àwọn èèyàn Kwara- Kọmiṣọnna ọlọ́pàá Kwara
24 Ẹrẹ̀nà 2026
Àwọn agbébọn kọlu ìjọ ECWA ní Kwara, wọ́n jí èèyàn mẹ́jọ gbé.
23 Ẹrẹ̀nà 2026
A gbọ́dọ̀ gba ilẹ̀ wa padà lọ́wọ́ àwọn agbèṣùmọ̀mí - ọ̀gá àgbà ọlọ́pàá Tunji Disu fọnmú
10 Ẹrẹ̀nà 2026
Àwọn agbébọn jí Ìmáàmù àti àwọn mẹ́rin míì gbé ní Kwara.
9 Ẹrẹ̀nà 2026
Àwọn ajínigbé jí àwọn tó ń ṣa kóró kaṣú àtàwọn tó ń la igi lóko gbé lọ ní Kwara, wọ́n ń béèrè fún N10m
8 Ẹrẹ̀nà 2026
Ọwọ́ ọlọ́pàá Kwara tẹ afurasí ọmọ ọdún mẹ́ẹ̀dọ́gún (15) kan tó ṣekú pa alágbàtọ́ rẹ̀ ní Kwara
7 Ẹrẹ̀nà 2026
Agbébọn padà sí agbègbè Woro ní Kwara, gbẹ̀mí èèyàn, jí oúnjẹ, fóònù, àti nǹkan míì kó lọ
2 Ẹrẹ̀nà 2026
Ìjàmbá iná ṣọṣẹ́ ní òtẹ́ẹ̀lì àwọn olówò nàbì ní Ilorin, oníbàárà kan jóná mọ́lé
1 Ẹrẹ̀nà 2026
Nítorí aṣọ ilé ẹ̀kọ́, bàbá akẹ́kọ̀ọ́ lọ lu olùkọ́ lálùbolẹ̀ ni Kwara
28 Èrèlè 2026
Àwọn agbébọn jí èèyàn mẹ́rin nínú ìdílé kan náà gbé ní Kwara
27 Èrèlè 2026
Àwọn agbébọn tún ṣekú pa èèyàn méjì ní Kwara, èèyàn kan f'arapa
24 Èrèlè 2026
Ẹ̀mí èèyàn méjì tún bọ́ lọ́wọ́ àwọn agbébọn ní Kwara
23 Èrèlè 2026
A lọ ya owó ni Báńkì àti lọ́wọ́ ará ìlú kí a tó rí owó ìtúsílẹ̀ Funke aya Aṣọgbó tí wọn pa ni Kwara san
18 Èrèlè 2026
1:34
Fídíò,
Ìbẹ̀rùbojo àti ìpayà ni àdó olóró Trump tó ṣèṣì balẹ̀ sínú Offa kó sí wa lọ́kàn - Aráàlú
, Duration 1,34
18 Èrèlè 2026
Aráàlú fi ìlú sílẹ̀ ní Kwara lẹ́yìn tí àwọn agbébọn kọ lẹ́tà pé àwọn ń bọ̀
16 Èrèlè 2026
Àwọn agbébọn tún kọlu agbègbè Kakafu àti Saare ni Kwara
16 Èrèlè 2026
Agbébọn ṣàfihàn fídíò ọ̀gọ̀rọ̀ èèyàn tí wọ́n jí gbé ní Kwara, wọ́n ní 176 làwọn jí gbé, kìí ṣe 32
15 Èrèlè 2026
Àwọn ajínigbé yọ̀nda àwọn mẹ́rin tí wọ́n jígbé ní Kwara
12 Èrèlè 2026
Ọwọ́ ọlọ́pàá Kwara tẹ afurasí ajínigbé tó múra bíi oníbárà
12 Èrèlè 2026
Ìjàmbá ọkọ̀ gba ẹ̀mí akẹ́kọ̀ọ́ KWASU tó fẹ́ ṣe ìdánwò àṣekágbá
8 Èrèlè 2026
Page
1
nínú
20
1
2
3
4
5
6
7
20
Tókàn