Fídíò òògùn ikọ́ Codeine: Àpọ̀jù rẹ̀ ń ya ọ̀dọ́ ní wèrè

Àkọlé fídíò, Fídíò òògùn ikọ́ Codeine: Àpọ̀jù rẹ̀ ń ya ọ̀dọ́ ní wèrè

Ọ̀pọ̀ ọ̀dọ́ ní orílẹ̀èdè Nàíjíríà ni ìwádìí abẹ́lẹ̀ tí iléesẹ́ BBC se ti fihàn pé ewu ńlá ń bẹ nínú mímu àpọ̀jù Òògùn ikọ́ olómi tó ní èròjà Codeine nínú.

Fídíò náà, tó bẹ̀rẹ̀ láti ìlú Kano dé Ìlọrin tú àsírí tó wà nínú títà àti títa Òògùn ikọ́ olómi Codeine ní Nàíjíríà.

Àkọlé àwòrán, Emzor ní òun ti ń se ìwádìí Chukwunonye Madubuike (ọwọ́ ọ̀tún)

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Àkọlé àwòrán, Àwọn ìgò oògùn ikọ́ olómi tó ní èròjà codeine ń polówó èròjà codeine tó wà nínú wọn