You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Agbèbọ́n tún ṣọṣẹ́ ní Plateau, pa ọ̀pọ̀ èèyàn lọ́jọ́ Ìsinmi Ọ̀pẹ ana.
Ilu Gari Ya Waye, lagbegbe Angwan Rukuba ni iṣẹlẹ naa ti waye.
Iroyin sọ pe ko din ni eeyan mejila ti wọn yinbọn pa, ti ọpọ si farapa yanna-yanna.
Gomina Caleb Mutfwang ti wa kede konileogbele ni Plateau bayii.
Ẹkunrẹrẹ wa loju opo wa.
lllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllll
Ajọ eleto idibo ilẹ wa, INEC ti gba orukọ awọn ti yoo dari PDP ninu igun Nyesom Wike wọle lẹyin ipade apapọ igun naa to waye l'Abuja
Oni ọjọ Aje ni INEC kede orukọ awọn igbimọ amuṣẹṣe tuntun ti igun Wike yan.
Lẹyin ti awọn kan ninu PDP ti kọyin sipade naa lai yọju sibẹ.
Abdulrahman Mohammed ni INEC kede bii alaga apapọ PDP.
Samuel Anyanwu ni Akọwe ẹgbẹ
Lọ soju opo BBC.COM/Yoruba lati mọ awọn to ku
llllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllll
N gbọ, Funke Akindele kọ lati da Toyin Abraham lohun nigba to ki i lode
Bẹẹ ni o, fidio ṣafihan bi Iya re ṣe n ki Funke amọ ti Jenifa leju pa
Lati mọ ohun to fa eyi