Eid Mubarak: Àràmọ̀ǹdà àwòràn ìkíni ọdún Eid il Fitr òṣèré tíátà Yorùbá àti gbajúmọ̀ míràn rèé

Jakejado Naijriia lawọn musulumi ti n ṣe ajọdun Eid il Fitr. Ko yọ awọn elere tiata ati gbajumọ mii silẹ.

Oríṣun àwòrán, Instagram/thecuteabiola

Àkọlé àwòrán, Akramaka llah! Ọmọ weri wenu taara ni Cute Abiola.

Oríṣun àwòrán, Instagram/mustiphasholagbade

Àkọlé àwòrán, Lati ilu Makkah ni Mustapha Sholagbade ti fi eleyi ranṣẹ sawọn musulumi pe wọn ku ọdun

Oríṣun àwòrán, Instagram/adebayo.salami

Àkọlé àwòrán, Ninu ki aworan yi wa lati ilu Alimi tabi ko si jẹ pe ni Ikorodu ni Oga Bello ti ki irun Yidi.Ki lẹyin ro?

Oríṣun àwòrán, Instagram/mydemartins/

Àkọlé àwòrán, Eleyi lawọn to gbafẹ n pe ni Sai Baba ati Sai Mama!

Oríṣun àwòrán, Instagram/mo_bimpe/

Àkọlé àwòrán, Idile Adedimeji Lateef naa n ki yin pe Barka da Sallah

Oríṣun àwòrán, Instagram/officialsalawaabeni

Àkọlé àwòrán, Ijiwumi, Salawa yi n kọrin tuntun...Lọjọ Ọdun Mama ni ka ki yin pe Barka da Sallah

Oríṣun àwòrán, instagram.com/realmercyaigbe/

Àkọlé àwòrán, Iyawo Alhaji naa tun ree

Oríṣun àwòrán, Instagram/realmercyaigbe

Àkọlé àwòrán, ''Iyawo Alhaji'' ni apejuwe ti Mercy Aigbe fi juwe aworan yi.Alhaji nkọ?

Oríṣun àwòrán, Instagram/ighalojude

Àkọlé àwòrán, Lati orileede Saudi naa leleyi ti wa. Jalabia Jude Ighalo ati awọn ọmọ rẹ yi n dawa lọrun!