Yusuf Buhari and Zahra Bayero wedding :wo àwòrán àwòdamiẹnu níbi ìgbéyàwó ọmọ ààrẹ Buhari

Awodamiẹnu ni aworan awọn to peju pesẹ sibi igbeyawo ọmọ aarẹ Naijiria Yusuf Buhari

Oríṣun àwòrán, Femi Adeshina

Àkọlé àwòrán, Godswill Akpabio ati ọkọ Iyawo Yusuf

Oríṣun àwòrán, MM

Àkọlé àwòrán, Yusuf ati iyawo rẹ Zahra

Oríṣun àwòrán, femi Adeshina

Àkọlé àwòrán, Yusuf Buhari ni ọmọ ọkunrin kan ṣoṣo ti aarẹ Buhari bi

Oríṣun àwòrán, Femi Adeshina

Àkọlé àwòrán, Igbakeji aarẹ Yemi Osinbajo naa ko gbẹyin nibi igbeyawo yi

Oríṣun àwòrán, Femi Adesina

Àkọlé àwòrán, Awọn to kọwọrin pẹlu aarẹ ninu wọn lawọn Gomina naa wa

Oríṣun àwòrán, Femi Adesina

Àkọlé àwòrán, Ọjaja Kini Ooni ile Ife naa ṣoju awọn oriade nibi igbeyawo Yusuf ati Zahra

Oríṣun àwòrán, Femi Adesina

Àkọlé àwòrán, Ibaṣepọ aarẹ tẹlẹ Jonathan ati aarẹ oni Muhammadu Buhari jẹ eleyi to dan mọran

Oríṣun àwòrán, Femi Adesina

Àkọlé àwòrán, Awọn iyawo aarẹ orileede to sunmọ Naijira wa yẹ iyawo aarẹ Aisha Buhari si nibi igbeyawo ọmọ rẹ

Oríṣun àwòrán, Femi Adesina

Àkọlé àwòrán, Awọn araalu jade la ti wa yẹ aarẹ si nibi igbeyawo ọmọ rẹ