Kogi àti Bayelsa: Èsì tó jáde láti ìpínlẹ̀ Kogi

Oríṣun àwòrán, Aseda Sunny Aseda

Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 1
Skip Facebook post

Content is not available

View content on FacebookBBC kò mọ̀ nípa àwọn ohun tí ó wà ní àwọn ojú òpó tí ó wà ní ìta.

End of Facebook post

Ìròyìn tó ń tẹ̀ wa lọ́wọ́lọ́wọ́ ní wí pé àjọ INEC ìpínlẹ̀ Kogi ti bẹ̀rẹ̀ si ni kédé èsì ìdìbò gómìnà ti ìjọba ìbílẹ̀ tó kù ṣáájú kíkéde ẹni tó jáwé olúborí.

Bo ṣe ń jáde rèé.

KOGI

BAYELSA

A n se akojọpọ ẹkunrẹrẹ iroyin yajoyajo lọwọ, a o maa gbe ẹkunrẹrẹ iroyin naa sori atẹ iroyin wa laipẹ. Ẹ jọwọ, ẹ tun oju opo iroyin yi yẹwo, ki ẹ lee ri ẹkunrẹrẹ iroyin ọtun laipẹ.