Nigeria independence day: Àwọn ọmọ Nàìjíríà ń sọ èrò wọn nípa àyájọ́ òmìnira lórí ayélujára

Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 1

Ọjọ ayajọ ọdun ominira Naijiria ni ọjọ akọkọ ninu oṣu kẹwaa gbogbo ọdun jẹ nitori ayajọ naa ni ọdun 1960 ni orilẹede Naijiria gba ominira rẹ kuro lọwọ ijọba amunisin ilẹ Gẹẹsi.

Ni ayajọ ọdun yii, oniruuru ara ni awọn ọmọ orilẹede Naijiria da lori ọkan o jọkan oju opo ayelujara.

Bakan naa lawọn kan naa tun n lo oniruuru ọrọ idakọro ori ayelujara iyẹn hashtag # bii #NigeriaAt59#IndependenceDay, #October1st,#naijaat59, #GodBlessNigeria, #ProudlyNigerian lati fi ero ọkan wọn han nipa ajọdun naa.