Orisabunmi: Iyaafin Fọlakẹ Arẹmu, Orisabunmi ti wọ káà ílẹ̀ sún

Akọjọpọ aworan lati aṣeyẹ isinku iyaafin Folake Aremu re e;

Àkọlé àwòrán, Gbajugbaja agba oserebinrin, Folake Orisabunmi ti jade laye.
Àkọlé àwòrán, Owurọ Ọjọru ni awọn akẹẹgbẹ rẹ kan bi Toyosi Adesanya bẹrẹ si ni ṣe idaro iku rẹ lori ayelujara Instagram wọn.

Ebi, ara, ojulumọ ati afẹnifẹre lo peju sibi isinku naa ni Olla Isin ni ipinlẹ Kwara.

Àkọlé àwòrán, A kò ti fidi igba to ku tabi nkan to pa a mulẹ lasiko ti a kọ iroyin yii, sugbọn ao ma mu ẹkunrẹrẹ iroyin wa fun yin to ba se n tẹ wa lọwọ.
Àkọlé fídíò, BBC findings on lekki shooting: Ẹ wa wo àwọn tó ṣì ń wá ẹbí wọn nínú ìṣẹ̀lẹ̀ End SARS 2020
Àkọlé àwòrán, Iroyin sọ pe ẹni ọgọta ọdun ni Oriṣabunmi ki o to jade laye.
Àkọlé àwòrán, Ọjọ Kẹwaa, oṣu Kẹwaa, ọdun 1960 ni wọn bi nilu Ola nipinlẹ Kwara.
Àkọlé àwòrán, Iya orisa, tabi ajẹ funfun ni orukọ ti ọpọ miran tun maa n pe e nitori awọn ipa ti o maa n ko ninu ere itage ati sinima.