Baba Suwe: Fún ojú lóúnjẹ nípa àwọn gbajúmọ̀ òṣèré tó yọjú síbi ìsìnkú Baba Suwe

Àkọlé àwòrán, Adebayo Salami

Oni, ọjọ karundinlọgbọn, oṣu Kje, ọdun 2021 ni babatude Omidina, ti ọpọ mọ si Baba Suwe wọ kaa ilẹ sun nile rẹ to wa ni Ikorodu, niluu Eko.

Awọn ẹbi, ọrẹ, aladugbo, to fi mọ awọn agba oṣere tiata Yoruba lo peju sibi eto isdinku adẹrinpoṣonu naa.

Ẹni ọdun mẹtalelọgọt\a ni Baba Suwe ko to dagbere faye lẹyin aisan ranpẹ gẹgẹ bii ohun ti ọkan lara awọn ọmọ rẹ okunri ṣalaye fu BBC.

Àkọlé àwòrán, Femi Adebayo
Àkọlé àwòrán, Kunle Adetokundo ti ọpọ mọ si Dejo Tunfulu
Àkọlé àwòrán, Jide Kosoko ree lasiko to de ile Baba Suwe
Àkọlé àwòrán, Aarẹ TAMPAN, Bolaji Amusan Mr latin naa wa nibẹ
Àkọlé àwòrán, Hassanat Akinwande ti ọpọ mọ si Yetunde Wumi
Àkọlé àwòrán, Fausat Balogun ti ọpọ awọn ololufẹ rẹ mọ si Madam Saje ko gbẹyin
Àkọlé àwòrán, Oluwasesan Adio ree ti ọpọ mọ si Ojoge
Àkọlé fídíò, Murphy Afolabi: Kò dùn mí tí wọn bá ṣe yẹ̀yẹ́ mi torí mò fi sí pe ṣí, èdè Osogbo ìlú mi ni