EidAlFitr2019: Bó ṣe ń lọ káàkiri àwọn Yidi rèé

Ẹ kú ọdún ìtúnu àaàwẹ̀ gbogbo ẹ̀yin olólùfẹ́ BBC Yoruba, a muú àwọn àwòrán bi àdúà ṣe ń lọ ni àwọn Yidi ni agbègbè wa.

Àkọlé àwòrán, Gomina Oyo nigba kan ri, Rasheed Ladoja naa de Yidi
Àkọlé àwòrán, Adua a gba o
Àkọlé àwòrán, Sultan ti Kano ati Gomina Ipinlẹ Kano pade ni Yidi
Àkọlé àwòrán, 'Baba, ẹ ba wa lọwọ adua'
Àkọlé àwòrán, Aarẹ Muhammadu Buhari ati ọmọ rẹ ọkunrin
Àkọlé àwòrán, Ti ẹṣiṣi ba fo gan nibi ti Aarẹ wa gan, awọn alaṣọ dudu wọnyii yoo han!
Àkọlé àwòrán, Ẹ ń lẹ́ ń bẹun o!
Àkọlé àwòrán, Bíntín logé ti ń bẹ̀rẹ̀
Àkọlé àwòrán, Ẹ gbé ìrun dúró
Àkọlé àwòrán, Awọn ọmọ ọlọdun ree to gan pa fun fọto
Àkọlé àwòrán, Awọn oniṣowo ko gbẹyin
Àkọlé àwòrán, Toju ko ba ri daradara, ẹ fi igo kaa.
Àkọlé àwòrán, Ọmọ Ibadan, ki ni so?
Àkọlé àwòrán, Awọn musulumi ododo nipinlẹ Ọyọ naa darapọ mọ awọn akẹgbẹ wọn lagbaye lati ṣe ajọyọ ọdun itunu awẹ.
Àkọlé àwòrán, Ibadan, Ipinlẹ Oyo
Àkọlé àwòrán, Ko si alaabọ ara niwaju Eleduwa
Àkọlé àwòrán, Yidi Ibadan ni Ipinlẹ Oyo