Àwòrán mánigbàgbé BBC news Yorùbá fún ọ̀sẹ̀ yìí

Èyí ni àkójọpọ̀ àwọn oun tí ojú wa rí ní ìgboro ní ọ̀sẹ̀ yí

Àkọlé àwòrán, Iṣẹ́ loógùn ìṣẹ́
Àkọlé àwòrán, B'ọ̀sàn bá dùn, máà mu igba
Àkọlé àwòrán, Ẹran ọbẹ̀ ní gbangba òde...
Àkọlé àwòrán, Àwọn ará Ipinlẹ Osun ko ilu síta láti ṣe ajọyọ idajọ ile ẹjọ kotẹmilọrun tó gbade fun Gboyega Oyetola ti APC
Àkọlé àwòrán, Dùndún, àkàrà tàbí ẹran díndín, ẹ mú tiyín níbẹ̀