Nigeria vs Argentina: Kìí dùn kópè, ó tún dìgbà kan ná

Ìfẹsẹ́wọnsẹ̀ náà f'ọwọ kàn òpó olólùfẹ́ Super Eagles l'ẹ́mìí

Oríṣun àwòrán, SEGUN OGUNFEYITIMI/AFP/Getty Images

Àkọlé àwòrán, Ẹkùn ló parí ọrọ ifẹsẹwọnsẹ náà fún arákùnrin yí ní ìlú Èkó

Oríṣun àwòrán, SEGUN OGUNFEYITIMI/AFP/Getty Images

Àkọlé àwòrán, Àwọn alatilẹyin Super Eagles orílèèdè Naijirià káwó lórí bí Argentina ṣe jẹ góòlù kejì

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Níbi tí ẹlẹkun tí n sunkún

Oríṣun àwòrán, @KelechiAFC

Àkọlé àwòrán, Kelechi Anyikude ro dédé kàn dudu ṣáájú ifẹsẹwọnsẹ Naijirià àti Argentina

Oríṣun àwòrán, oluwakaponeski/instagram

Àkọlé àwòrán, Alawada Oluwakoponeski fi àwòrán yí níbi tó tí dákú ṣòwò lójú òpó Twitter.

Oríṣun àwòrán, @ASRomaEN

Àkọlé àwòrán, Ẹgbẹ agbaboolu AS Roma fí ọrọ ìkíni ranṣẹ sójú òpó Twitter wọn sì ìkọ Super Eagles

Oríṣun àwòrán, YASUYOSHI CHIBA/AFP/Getty Images

Àkọlé àwòrán, Lorílè-èdè Kenya,àwọn ọmọ ilẹ áfíríkà gbe lẹyìn Super Eagles sugbọn ẹpa kòo boro mọ

Oríṣun àwòrán, Abubakar Siddiq Usman

Àkọlé àwòrán, Awakọ bàálù tí yóò gbé wọn padà wálé tí wà ní ṣepe