TB Joshua Death: Àwòrán bí ó ṣe ńlọ rèé níbi ìsìnkú TB Joshua lónìí

Akojọpọ aworan re e lati ibi isinku Woli TB Joshua

Àkọlé àwòrán, Temitope Balogun Joshua jẹ oniwaasu ati wolii lorilẹede Naijiria to da Ijọ Synagogue Church of All Nations
Àkọlé àwòrán, Ọjọ Kẹfa, Osu Keje, ọdun 2021 ni Woli TB Joshua jade laye ni ẹni ọdun mẹtadinlọgọta
Àkọlé àwòrán, Gbogbo eto lo ti to fun titẹ oku TB Joshua si gbangba fun awọn eniyan lati ri
Àkọlé àwòrán, An eniyan jankan jankan lo tẹle posi rẹ wọ ile ijọsin Synagogue ti wọn tẹ ẹ si
Àkọlé àwòrán, Ọpọ eniyan lo pejọ si ile ijọsin naa lati ṣe ẹyẹ ikẹyin fun.

Oríṣun àwòrán, Emmanuel TV/Facebook

Akojọpọ aworan yii wa lati ileeṣẹ BBC News Yoruba

Awọn iroyin ti ẹ le nifẹ si

Àkọlé fídíò, 'Ìjámbá Ọ̀kadà ló dédé sọ mi di òdi, ìyàwó tí mo yó ìfẹ́ rẹ̀ náà tún wá jẹ́ odi'