Onísòwòo Nàìjíríà àti South Africa ń ṣe ìpàdé nígbà tí Ààrẹ Buhari lọ sí South Africagbà

Ẹ wo bí ìpàdé àwọn oníṣòwòo Nàijíríà àti South Africa ṣe ń lọ lórílẹ̀èdè Gúúsù Afrika naa nígbà tí Ààrẹ Buhari ń ṣe àbẹ̀wò síbẹ̀.

Àkọlé àwòrán, Abílékọ Lovina Kayode láti àjọ tó ń rí sí ìdàgbà s'ókè ìdókòwò Nàìjíríà ń s'ọ̀rọ̀ nípa ìdókòwò ní Nàìjíríà
Àkọlé àwòrán, Ambassador Sadick Jaffer, adarí ńlá láti Àjọ òwò àti ilé iṣẹ́ẹ South Africa
Àkọlé àwòrán, Àwọn onísòwò láti orílẹ̀èdè méjéjì ń gbọ́ ọ̀rọ̀ nípa àǹfàní tó wà níbi òwò ní orílẹ̀èdè méjéjì.
Àkọlé àwòrán, Láìpẹ́ yìí ni ìbáṣe láàrin Nàìjíríà àti South Afrika bàjẹ́ látàri bí wọ́n ń ṣe ń kọlu àwọn ọmọ Nàìjíríà ní orílẹ̀èdè náà, Onísòwòo Nàìjíríà àti South Africa ń ṣe ìpàdé ní South Africa
Àkọlé àwòrán, Oríẹ̀èdè méjéjì ń gbìnyànjú láti gbàgbé ọ̀rọ̀ ìjà ẹlẹ́yàmẹyà tó ṣẹlẹ̀ láàrin wọn láìpẹ́ yìí
Àkọlé àwòrán, Ààrẹ Muhammadu Buhari ń ṣe àbẹ̀wò sí orílẹ̀èdè náà l'Ọ́jbọ àti ọjọ́ Ẹtì
Àkọlé àwòrán, Abílékọ Lovina Kayode láti àjọ tó ń rí sí ìdàgbà s'ókè ìdókòwò Nàìjíríà ń s'ọ̀rọ̀ nípa ìdókòwò ní Nàìjíríà

Oríṣun àwòrán, @Govt ZA

Àkọlé àwòrán, Awọn eniyan South Africa n duro ki Arẹ Buhari

Oríṣun àwòrán, @Govt ZA

Àkọlé àwòrán, Aarẹ Buhari n ki awọn minista Ramaphosa ni Pretoria ni South Africa

Oríṣun àwòrán, @GovtZA

Àkọlé àwòrán, Aarẹ Buhari n ki awọn ti Aarẹ Ramaphosa South Africa jọ n ṣejọba