Ilé ẹjọ́ gíga kún fọfọ lori igbẹ́jọ́ Omoyele Sowore l'Abuja

Awọn agbẹjọro ti wa ni ikalẹ ti wọn si n reti adajọ ati Sowore ti wọn fẹsun kan lati yọju si ile ẹjọ giga l'Abuja

Àkọlé àwòrán, Agbẹjọro Femi Falana wa nikalẹ fun Omoyẹle Soworẹ
Àkọlé àwòrán, Deji Adeyanju,ajafẹtọmọniyan naa wa nile ẹjọ fun Soworẹ
Àkọlé àwòrán, Ilẹ ẹjọ kun fọfọ ti awọn akọroyin si n duro de adajọ
Àkọlé àwòrán, Wọn ti fi Sowore si ahamọ lati igba ti wọn ti mu loṣu Kẹjọ ọdun 2019
Àkọlé àwòrán, Awọn agbẹjọro ti wa ni ikalẹ ti wọn si n reti adajọ ati Sowore ti wọn fẹsun kan lati yọju si ile ẹjọ giga l'Abuja