Ọdún ìjẹṣu: Ẹ wo Àwòrán mánigbàgbé níbi ọdún Ìlárá-Mọ́kín ní ìpìnlẹ̀ Ondo

Àwọn ọmọ ìlú Ìlárá-Mọ́kín ní ìpìnlẹ̀ Ondo ló wá láti ìtòsí àti ọ̀nà jínjìn láti kópa nínú ọdún ìjẹṣu ti ọdún yìì.

Àkọlé àwòrán, Pẹlu ijo ati ayọ ni wọn fi ṣe ọdun ọhun.
Àkọlé àwòrán, Awọn omidan ati abilekọ ilu Ilara-Mọkin ko gbẹyin nibi ọdun naa.
Àkọlé àwòrán, Awọn ọdọ ilu Ilara-Mọkin ko gbẹyin ni ibi ọdun ijṣẹsu na.
Àkọlé àwòrán, Awọn ọmọ ilu naa wa lati ibi gbogbo lati kopa ninu ọdun ijẹṣu naa.
Àkọlé àwòrán, Imura fun ọdun ijẹṣu naa ko kere.
Àkọlé àwòrán, Àwọn lọba lọba ati ijoye ko gbẹyin ni ibi ọdun ijẹṣu ọhun.
Àkọlé àwòrán, Ẹgba jijẹ wa lara awọn ohun arimaleelọ ni ibi ọdun ọhun.
Àkọlé àwòrán, Àwọn èèyàn Ìlú Ilara-Mọkin nnibi ọdun ijẹṣu naa