Swearing in 2019: Àga, àsìá, àtìbàbà àti ẹní àtẹ́ẹ̀ká ti wà nílẹ̀ fún ìbúra

Ọjọru ọjọ Kọkandinlọgbọn o'su Karun ọdun 2019 ni ayẹyẹ ibura yoo waye Fun aarẹ Muhammadu Buhari ni ilu Abuja.

Oríṣun àwòrán, Musictori

Àkọlé àwòrán, Ori pepele yii ni akọsilẹ itan miran yoo tun ti waye nigba ti Buhari ba ṣe ibura fun saa keji lori rẹ

Oríṣun àwòrán, Musictori

Àkọlé àwòrán, Ori pẹpẹ yii ni eto ibura yoo ti waye fun aarẹ Buhari lọla

Oríṣun àwòrán, Musictori

Àkọlé àwòrán, Alaga ọlọla ree fun awọn alejo pataki ti yoo peju sibi ibura aarẹ Muhammadu Buhari

Oríṣun àwòrán, Musictori

Àkọlé àwòrán, Ẹni atẹẹka to wọle sibi gbagede ibura ree ti aarẹ atawọn eeyan pataki miran yoo gba kọja

Oríṣun àwòrán, Musictori

Àkọlé àwòrán, Awọn ohun ase ibudo lọṣọ ti wa nikalẹ nibi ibudo ayẹyẹ ibura

Oríṣun àwòrán, Musictori

Àkọlé àwòrán, Ẹni ti yoo jẹun gbọin-gbọin yoo tilẹkun gbọin-gbọin lọrọ ipese eto aabo ni ibudo ibura ti yoo waye lọla

Oríṣun àwòrán, Musictori

Àkọlé àwòrán, Ilu Abuja ti dun wo pẹlu oniruuru aramọnda ọṣọ to gba oju popo kan