Àwọn àwòrán tó làmìlaaka níbi ayẹyẹ àpéjẹ ìdúpẹ́ Aisha Buhari

Àwọn ènìyàn jàǹkàǹjàǹkàǹ ló pé jú síbi ayẹyẹ àpéjẹ ìdúpẹ́ Aisha Buhari tó wáyé nílé ìjọba l'Abuja.

Oríṣun àwòrán, @aishambuhari

Àkọlé àwòrán, Aisha Buhari ni o wu ohun lati pe gbogbo awọn to dibofun Aarẹ Buhari wa si ibi apejẹ naa

Oríṣun àwòrán, @aishambuhari

Àkọlé àwòrán, Iyawo Igbakeji Aarẹ Dolapo Osinbajo wa nibi ayẹyẹ naa

Oríṣun àwòrán, @aishambuhari

Àkọlé àwòrán, Aisha ba awọn ọdọkunrin ya aworan nibi ayẹyẹ naa

Oríṣun àwòrán, @aishambuhari

Àkọlé àwòrán, Awọn oṣere tiatia Yoruba naa ko gbẹyin

Oríṣun àwòrán, @aishambuhari

Àkọlé àwòrán, Oga Bello,Jide Kosoko ati Ebun Oloyede naa peju sibẹ

Oríṣun àwòrán, @aishambuhari

Àkọlé àwòrán, Oju tiyin emi ni Aisha bibo fun un o !

Oríṣun àwòrán, @aishambuhari

Àkọlé àwòrán, Awọn oṣere tiatia obinrin naa wa nibi ayẹyẹ naa