Àwọn ènìyàn jàǹkàǹ-jàǹkàǹ pésẹ̀ síbi ayẹyẹ àádọ́rùn ọdún Olubadan

Bí ó ṣe lọ rèé níbi àṣekágbá ayẹyẹ ọjọ́ ìbí àádọ́rùn ọdún Olubadan, Ọba Saliu Adetunji, ni gbọ̀ngàn ńlá ìgbàlejò fasitì ìlú Ibadan

Àkọlé àwòrán, Ayẹyẹ ọjọ́ ìbí àádọ́rún ọdún Olubadan, Oba Saliu Adetunji
Àkọlé àwòrán, Aṣo òkè, aṣọ àtìgbà ìwásẹ̀ tó tún bá tìgbàlódé mu ni baba wọ fi gbé àṣà Yoruba ga
Àkọlé àwòrán, Ẹni ọdun ba ba laye, yẹ ko dupẹ fun ẹmi ati alaafia
Àkọlé àwòrán, Akara oyinbo aláràbarà ni Alaṣẹ ikeji Oriṣa ge
Àkọlé àwòrán, Àwọn ènìyàn jàǹkàǹ-jàǹkàǹ pésẹ̀ síbi ayẹyẹ àádọ́rùn ọdún Olubadan
Àkọlé àwòrán, Aàwọ búlù ló dabi pe ọpọ ninu àwọn alejo naa pe fun ra wọn, gèlè lo n pe gèlè ran niṣeẹ yii
Àkọlé àwòrán, Ibi gẹrẹjẹ làá bá àgbà, ọjọ́ àwọn arugbo wa a dalẹ́
Àkọlé àwòrán, Olubadan ṣe tọdun yii ná, gbọngan àwò-dami-ẹnu ni
Àkọlé àwòrán, Lootọ, aṣọ Yoruba yẹ àwọn èèyàn , E wo gbogbo èrò bi wọn ṣe dùn la'ti wò