Ìgbeyàwó Fayose: Ìjó Shaku-shaku ni gómìnà fi dárayá

Igbeyawo alarinrin naa waye laarin Tomilọla Fayose ati Arẹwa Ọdunlade lọjọ Satide, ọjọ kejidinlogun, osu kẹjọ ọdun 2018.

Oríṣun àwòrán, @GovAyoFayose

Àkọlé àwòrán, Asọ oyinbo ni gomina wọ lati fa ọmọ rẹ fun ọkọ ni kootu

Oríṣun àwòrán, @GovAyoFayose

Àkọlé àwòrán, Baba ati iya iyawo ni wọn se bii oloyinbo nibi igbeyawo oloruka ti Tomi Fayose ati Arẹwa Ọdunlade se

Oríṣun àwòrán, @GovAyoFayose

Àkọlé àwòrán, Awọn ẹbi tọkọ-taya tuntun ti parada si asọ ibilẹ wa

Oríṣun àwòrán, @GovAyoFayose

Àkọlé àwòrán, So bẹbẹ fẹ, abi o ko bẹbẹ fẹẹ ? Mo bẹbẹ fẹ ni ọkọ iyawo atawọn ọrẹ rẹ n sọ.

Oríṣun àwòrán, @GovAyoFayose

Àkọlé àwòrán, Ọmọ to jọ ‘Daddy’ gan ree., oju to n sọrọ

Oríṣun àwòrán, @GovAyoFayose

Àkọlé àwòrán, Ololufẹ, maa fẹ ọ titi aye ni tọkọ-taya tuntun n sọ fun ara wọn

Oríṣun àwòrán, @Emmadex

Àkọlé àwòrán, Ijo shaku-shaku baba iyawo yii, ara ọtọ ni

Oríṣun àwòrán, @Eletiọfẹ

Àkọlé àwòrán, Haa, o ga ju. Fayose ko kẹrẹ ninu ijo Shaku-shaku

Oríṣun àwòrán, @GovAyoFayose

Àkọlé àwòrán, Iyawo yoo bi isun, yoo bi iwalẹ

Oríṣun àwòrán, @sleem_nation

Àkọlé àwòrán, Iya ati baba mo mi lọ, ẹfi adura sin mi o

Oríṣun àwòrán, @Emmadex

Àkọlé àwòrán, Tomilọla, ile ọkọ ya, ki ẹlẹda awọ̀n obi rẹ sin ọ lọ

Oríṣun àwòrán, @MonteOzAfrica

Àkọlé àwòrán, Iyawo dun lọsingin, ọkọ tun mi gbe