Àwòrán ọ̀pọ ohun tó bàjẹ́ ní iléesẹ́ rédíò Yinka Ayefẹlẹ

Ko si ẹni ti yoo de ileesẹ redio Fresh Fm tijọba ipinlẹ Ọyọ wo, ti ko ni mọ pe aimọye milliọnu naira lo run sibẹ.

Àkọlé àwòrán, Owurọ kutu hai, ni aago mẹrin owurọ ni ijọba wo ileesẹ redio Fresh Fm to jẹ ti Ayefẹlẹ
Àkọlé àwòrán, Haa, idi ikoko, ibiti owo run si lo bajẹ yii
Àkọlé àwòrán, Awọn eeyan ko ro ti ọjọ isinmi, wọn pejọ lati foju se mẹrin isẹlẹ naa
Àkọlé àwòrán, Ko si ibiti kata-kata da si lara ile naa
Àkọlé àwòrán, Eyin ka, ile ẹrin wo
Àkọlé àwòrán, Ferese gan subu lulẹ, to fi mọ asọ oju ile
Àkọlé àwòrán, Bi ile n jo, bi ojo n rọ, awọn ‘Ayafọto’ yoo kuku sisẹ wọn
Àkọlé àwòrán, Ẹsẹ ko gba ero nibi ile to wo
Àkọlé àwòrán, Ile to rẹwa tẹlẹ, wa di ile alapa bayii
Àkọlé àwòrán, N jẹ atunse wa fun ile yii mọ ?
Àkọlé àwòrán, Haa, nkan se
Àkọlé àwòrán, Awọn onworan gan bu sẹkun
Àkọlé àwòrán, Irinsẹ kata-kata tijọba lo lati wo ileesẹ redio Ayefẹlẹ