Wọn yi ni aworan ìṣẹlẹ òṣùpádẹ̀jẹ̀ káàkiri àgbáyé

Ẹwò àwòrán ìṣẹlẹ òṣùpádẹ̀jẹ̀ káàkiri àgbáyé.

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Aworan ìṣẹlẹ òṣùpádeje ni Germany

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Awọn eeyan n fi awo wo aworan ìṣẹlẹ òṣùpádeje ni Taiwan

Oríṣun àwòrán, MOHAMMED MAHJOUB/AFP/Getty Images

Àkọlé àwòrán, Aworan ìṣẹlẹ òṣùpádeje lorileede Oman

Oríṣun àwòrán, GIUSEPPE CACACE/AFP/Getty Images

Àkọlé àwòrán, Aworan ìṣẹlẹ òṣùpádeje ni Dubai

Oríṣun àwòrán, olayemi Patrick Edema

Àkọlé àwòrán, Adupe! Olayemi Patrick Edema naa ti ri ni Naijiria

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Aworan ìṣẹlẹ òṣùpádeje lorílè-èdè Turkey

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Aworan ìṣẹlẹ òṣùpádeje ni Cairo,Egypt

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Aworan ìṣẹlẹ òṣùpádeje nilu Ọba