Hajj 2018: Àwòrán bí àwọn Alálàájì àkọ́kọ́ ṣe ń gbéra l’Abuja

Àwọn alálàájì láti ìpínlè Kogi ni wọ́n ṣíde ìrìnàjò Hajj 2018 ní orílè-èdè Nàìjíríà.

Oríṣun àwòrán, NAHCON

Àkọlé àwòrán, Papakọ ofurufu Nnamdi Azikwe ni awọn arinrin-ajo naa yoo ti gbera

Oríṣun àwòrán, NAHCON

Àkọlé àwòrán, Àyẹwò fínífíní fún àwọn arinrin-ajo ṣe pàtàkì

Oríṣun àwòrán, NASA

Àkọlé àwòrán, Hajj je opo pataki ninu ẹsin Islam

Oríṣun àwòrán, NAHCON

Àkọlé àwòrán, Awọn osisẹ ile isẹ alalaji wa nikalẹ lati ri pe oun gbogbo lọ ni irọwọrọsẹ

Oríṣun àwòrán, NAHCON

Àkọlé àwòrán, Oko ofurufu ti yoo gbe awọn alalaji naa

Oríṣun àwòrán, NAHCON

Àkọlé àwòrán, Mínístà fún ìlú FCT Mohammed Bello ati alága àjọ tó n mójú tó ọrọ Alalaaji ní orílèèdè Nàìjíríà Abdullahi Mukhtar Muhammad ní papako òfurufú Nnamdi Azikiwe labuja

Oríṣun àwòrán, NAHCON

Àkọlé àwòrán, Aarẹ Buhari ni awọn mu eto aabo awọn ọmọ ilẹ Naijiria