Ekiti Election: Àkójọpọ̀ àwòrán bi idibo se n lọ ni Ward ati Unit

Ètó gbogbo ti n lọ ní ìdìbò gómìnà tí oun lọ lọwọ ni ìpínlẹ̀ Ekiti lọ́jọ́ Satide, Ọjọ Kẹrinla, ọdun 2018.

Àkọlé àwòrán, Awọn oludibo pejọ lati wo orukọ wọn saaju ayẹwo orukọ rẹ.
Àkọlé àwòrán, Owuro yii ni wọn se ayẹwo orukọ, ki idibo to bẹrẹ ni pẹrẹwu lati yan gomina mii dipo Ayọdele Fayọse
Àkọlé àwòrán, Oni loni n jẹ, ẹni a bẹ lọwe lori eto idibo ni ipinlẹ Ekiti
Àkọlé àwòrán, Ètó gbogbo ti n lọ ní ìmúra sílẹ̀ fún ìdìbò gómìnà to n sẹlẹ lọwọlọwọ ní ìpínlẹ̀ Ekiti
Àkọlé àwòrán, Ayẹwo orukọ n lọ lọwọ ni awọn Ward ati Unit to wa kaakiri ipinlẹ Ekiti
Àkọlé àwòrán, Akanda kan niyi ti Ko mo ibi ti yoo teka si