Ekiti Election: Èyí ń rán wa létí pé iná èèsì kò gbọdọ̀ jó wa ní ẹ̀ẹ̀kejì

Awọn aworan yii lo n sọ nipa awọn isẹlẹ̀ to waye lọdun 2014 lasiko eto idibo gomina ni ipinlẹ Ekiti.

Oríṣun àwòrán, @EkitiGovt

Àkọlé àwòrán, Ẹni to wa lẹgbẹ to n sejọba lọwọ ni 2014, lo jẹ oludije fun ẹgbẹ alatako bayii

Oríṣun àwòrán, @EkitiGovt

Àkọlé àwòrán, Gaga lara awọn eeyan ya lati dibo

Oríṣun àwòrán, @EkitiGovt

Àkọlé àwòrán, Ẹni ti aye n fẹ, kii ni abuku kan lara

Oríṣun àwòrán, @EkitiGovt

Àkọlé àwòrán, Ẹni ti ko lee rin, ni ki wọn wọ oun lasiko ipolongo ibo

Oríṣun àwòrán, @InecOfficialNg

Àkọlé àwòrán, Oju ri lọjọ ibo

Oríṣun àwòrán, @dan-f

Àkọlé àwòrán, Ẹbọ gbigbe kan ko gbẹyin lasiko ibo

Oríṣun àwòrán, Kolawole Amusat Gbenla

Àkọlé àwòrán, Oludije kan n lu ilu fawọn eeyan jo

Oríṣun àwòrán, Kolale Amusat Gbenla

Àkọlé àwòrán, Ọ́pọ eeyan wọ oorun sori lati dibo

Oríṣun àwòrán, Kokoirin layinka

Àkọlé àwòrán, Awọn osisẹ ajọ eleto idbo sisẹ kara

Oríṣun àwòrán, Kokoirin layinka

Àkọlé àwòrán, Kii se igba akọkọ ree tawọn agbofinro yoo peju sibi eto idibo, o ti waye saaju

Oríṣun àwòrán, Kolawole Amusat Gbenla

Àkọlé àwòrán, Tarugbo-tomidan lo jade lati dibo

Oríṣun àwòrán, Jerome Olowoye

Àkọlé àwòrán, Oludije kan ami iifẹ ati atilẹyin lọ̀wọ ololufẹ rẹ kan

Oríṣun àwòrán, Jerome Olowoyeye

Àkọlé àwòrán, Bi awọn olodije gomina se wọ ayẹta ni 2014, naa lawọn oludije goomina ni 2018 tun n wọ ayẹta ni Elkiti

Oríṣun àwòrán, Kolawole Amusat Gbenla

Àkọlé àwòrán, Bi oludije kan se n gba oriyin, naa ni omiran n gba