World Cup 2018: Ahmed Musa di ààyò ní Naijiria

Oniruuru aworan Ahmed Musa ni awọn ọmọ Naijiria ya si ara nkan ni orisirisi.

Oríṣun àwòrán, @Phillip

Àkọlé àwòrán, Bi eegun ẹni ba jo re, ori a maa ya atọkun rẹ. Awọn ọmọ Naijiria n pe Ahmed Musa ko wa jẹ aarẹ Naijiria

Oríṣun àwòrán, @bukolamainassara

Àkọlé àwòrán, Naijiria fun Musa ni tikẹẹti lati dije du ipo Aarẹ lọfẹ lori ayelujara

Oríṣun àwòrán, @FIFAWorldCup

Àkọlé àwòrán, Ahmed Musa di aayo agbabọọlu tawọn ọmọ Naijiria n wari fun

Oríṣun àwòrán, @Concaholic

Àkọlé àwòrán, Ahmed Musa lawọn ọmọ Nigeria ri bii Olugbala ni gbogbo ẹka

Oríṣun àwòrán, @Phatill

Àkọlé àwòrán, Koda awọn ọmọ Naijiria tun wwe Lawani fun Ahmed Musa gẹg bii alasẹ wọn

Oríṣun àwòrán, @dhe_Mechanic

Àkọlé àwòrán, Ọkunrin yii ni Ahmed Musa lo jẹ ki faanu ge oun lọwọ nigba to fo soke nitori ayo ti Musa gba wọle

Oríṣun àwòrán, @Can_caworm

Àkọlé àwòrán, Saaju idije Super Eagles pẹlu Iceland ni ọkan awọn ọmọ Naijiria ko ti balẹ, wọn n gbadura si Ọlọrun ko ko awọn yọ

Oríṣun àwòrán, @Phillip

Àkọlé àwòrán, Bi eegun ẹni ba jo re, ori a maa ya atọkun rẹ. Awọn ọmọ Naijiria n pe Ahmed Musa ko wa jẹ aarẹ Naijiria