Ọmọge Campus: Àwọn ọmọ, ẹbi, ara ati ọrẹ ló sìnkú Aisha

Òseré náà jáde laàyé ní ọjọ́ Ọjọ́rú nitorí àìsàn jẹjẹrẹ ọyàn ni ile rẹ̀ ní Canada.

Oríṣun àwòrán, LOLA ALAO/INSTAGRAM

Àkọlé àwòrán, Heritage Funeral Center ni wọn ti ṣe ayẹyẹ ráńpẹ́ náà ní Ọjọ́bọ ní Toronto

Oríṣun àwòrán, LOLA ALAO/INSTAGRAM

Àkọlé àwòrán, Ọ̀rẹ́ olóògbé, Lola Alao wa nibẹ̀ pẹ̀lu awọn ẹbí

Oríṣun àwòrán, LOLA ALAO/INSTAGRAM

Àkọlé àwòrán, Àwọn ọ̀rẹ́ olóògbé kò gbẹ́yìn níbẹ̀

Oríṣun àwòrán, LOLA ALAO/INSTAGRAM

Àkọlé àwòrán, Ìsìn ìsìnkú Aisha Abimbola

Oríṣun àwòrán, LOLA ALAO/INSTAGRAM

Àkọlé àwòrán, Àwọm ẹbí rẹ̀ ṣe ìpìnnu láti sin òkú rẹ̀ sí Canada

Oríṣun àwòrán, LOLA ALAO/INSTAGRAM

Àkọlé àwòrán, Àìsàn jẹjẹrẹ ọyàn ni ó pa Aisha Abimbola ní Canada

Oríṣun àwòrán, LOLA ALAO/INSTAGRAM

Àkọlé àwòrán, Àwọn óṣeré tiáta Yoruba kò gbẹ́yìn ni bi ìsìn ìsìnkú Aisha Abimbola

Oríṣun àwòrán, LOLA ALAO/INSTAGRAM

Àkọlé àwòrán, Ìsìn ìsìnkú Aisha Abimbola