Ààrẹ Túnisia kú sẹyin odi lẹ́ni ọdun mẹtalélọ́gọ́rin

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Ààrẹ Túnisia kú sẹyin odi lẹ́ni ọdun mẹtalélọ́gọ́rin

Ààrẹ Tunisia nígbà kan rí President Zine el-Abidine Ben Ali tí kú sí ẹ̀yin odi lẹ́ni ọdun mẹ́tàlélọ́gọ́rin.

Ben Ali tó dari orílẹ̀-ede náà fún ọdún mẹ́talélógun, sùgbọ̀n gbogbo ìlú mọ̀ọ́ si ẹni to mu ìlọsíwáju ba ètò ọ̀rọ̀ ajé orilẹ̀-èdè náà.

Àkọlé fídíò, 'Mo fọ kọ́mú, pátá, ògiri ilé lórí 200,000 láìlèfọhùn lórílẹ̀èdè Oman'
Àkọlé fídíò, South Africa: Àwọn ọmọ Nàìjíríà tó kù ní ìjọba SA ń kó ọ̀pọ̀ tó fẹ́ wále sí ọgbà ẹ̀wọ̀n

Sùgbọ́n ọ̀ps lo n náwọ àtako nítori ó n tako òṣèlú awa ara waàti ìwà àjẹbánu.

Ní ọdun 2011, wan le kuro nílu pèlú ìfẹ̀honu han, èyi lo si far rogbodiyan lorisirisi ni ààrin àwọn ẹya Arab.