Buhari In Lagos: Àwọn àwọran málegbàgbé ìpolongo ìbo ààrẹ ní'lú Eko

Awọn eleto ilera o gẹ́yìn bi a ṣe ri wọn níbi ti wọn ti ń toju ẹnikan to dáku lójíji.

Àkọlé àwòrán, Ààrẹ MuhamaduBuhari balẹ̀ sí ìlú Teslim Balogun Surulere ni Ipinlẹ Eko, ní bi ti ọ̀ps àwọn èniyàn ti ṣe àyẹ́si ààrẹ
Àkọlé àwòrán, Àwọn ará Ekó ń ki ààrẹ káàbs si ìlú Eko
Àkọlé àwòrán, Gbogbo àwọn èèkàn ẹgbẹ́ òṣèlú APC ló pé ju si ibi eto na, láti ori igbakeji ààrẹ prof Yemi Osinbajo, Bola Tinubu, Oloye Bisi Akande rotimi Ameachi, Raji Fashola, Akinwumi Ambode
Àkọlé àwòrán, Awọn eleto ààbo láti rii dáju pe janduku ò gba àkóso ètò náà
Àkọlé àwòrán, Awọn eleto ilera o gẹ́yìn bi a ṣe ri wọn níbi ti wọn ti ń toju ẹnikan to dáku lójíji
Àkọlé àwòrán, Ọpọ àwọn obinrin dásọ alara ń barà fún ààrẹ Buhari
Àkọlé àwòrán, Agbo ìpolongo yìí rẹwa pẹlú àwọn ohun iṣe lọ́sọ̀ọ́ ti wọn ṣe síbẹ̀
Àkọlé àwòrán, Ẹlẹgbẹ́ ń jẹ́gbẹ́ làwọn to péjú síbẹ̀
Àkọlé àwòrán, Ayọ àwọn ọdọ́ kan kò ṣe e fi pamọ, bẹ́ẹ̀ ni wọn

Oríṣun àwòrán, Bashir Ahmed

Àkọlé àwòrán, Ààrẹ Buhari ní gbọngan ìpolongo ibo ní ìpínlẹ̀ Eko, ni bi ti o ti n rọ àwọn ara ilu láti duro ti ibo wọn lẹyin ti wọn ba ti se ojuse wọn tan lọ́sẹ̀ tó ń bọ

Oríṣun àwòrán, Bashir Ahmed

Àkọlé àwòrán, Ọ̀pọ̀ àwọn gómìnà ìpínlẹ ló péju sibi àyẹyẹ ìpolongo tó wáye ní'lú Eko